Suru La Fi Nsoko Obinrin Lyrics
- Genre:Juju
- Year of Release:1988
Lyrics
Suru La Fi Nsoko Obinrin - Chief Commander Ebenezer Obey
...
suru lafin soko obinrin
suru lafin soko obinrin
agba to ni suru ohun gbogbo Loni
agba Toni suru ohun gbogbo Loni
Suru lafin soko obinrin
okinrin kan wa baba toyin lounje
oni mama kan mama toyin ni
Ife won po pupo
Ko se ko rara
Won kin n ba ra won ja
Aye ori arin won
Ife baba toyin
Opo si mama toyin oo
Okunrin kan nbe
Ma daru loruko re
O nwa na lati tu won ka o