Loading...

Download
  • Genre:Juju
  • Year of Release:1977

Lyrics

Awa dupe

Lowo oba oluwa wa

Iyin ni fun

Baba wa loke

Awa dupe

Lowo oba oluwa wa

Iyin ni fun

Baba wa loke


Ope ni fun

Oba to da wa

To soun gbogbo

Toju toju leni wa

Awa dupe

Lowo oba oluwa wa

Iyin ni fun

Baba wa loke

Ojomode o

E ma sole

Ise losupa se

Laijule orun

Ojomode o

E ma sole

Nini owo o

Adara ni

Aini owo o

Adara ni

A ke soluwa

Ko fun mi ni temi

Aiye kokoluwa

Ko fun e ni ti e

Nini owo o

Adara ni


Aye eleyi o

Aye faaji ni

Ayeyi o

Aye faaji ni

Aye yi o

Aye faaji ni

Aye yi o

Aye faaji ni

Aye yi o

Aye faaji ni

Aye ti mo wa

Aye faaji

Aye jelenke

Aye yi o

Aye faaji ni

Aye ti mo wa

Aye faaji

Aye jelenke

Aye yi o

Aye faaji ni


Kan to fiyan joye laarin ilu

O lati jeni rere

Ka to fiyan joye laarin egba

O lati jeni rere

Iyen lo boba

Ni egbe le mi o

To fi fomo abiola joye

MKO omo abiola

Won fabiola joye

Boba biwa iru egba

Abiola ti joye

Boba bu agba wa loje

Ajejumobi ogun jijun

Kan to fiyan joye laarin ilu

O lati jeni rere

Ka to fiyan joye laarin egba

O lati jeni rere

Onitemi abiola

Moshood ni baba loje

Ose f’alejo

O tun se f’onile

Oun ba omode se

Oun ba agbalagba se

Oun ba okunrin se

Oun se f’omode

Pele alagba abiola

T’enikan di te si ese

Iru kan ti oun lo yen

Ti e ni ko ma balo

T’enikan di te si ese

Iru kan ti oun lo yen

Ti e ni ko ma balo

Eni to wiwi omo abiola

Iyen ni t’afopina

Won ku aleje simiyato

Atinuke olamu

Eni to binu olorun dudu

Iyen ni t’afopina

Eni to keru eja si kan gbadura

Iyen ni t’afopina

Ah ewa wo afopina

Ajetumobi

Ewa wo afopina

Oloun o pa fitna

Mapa mua ni o

Ara eni 2x

Ara eni o pa

Ajetumobi nko

Ara eni 2x

Ara eni o pa

Gbajumo ara to jeun ajumo asa

Olowo jeun gbogbo tan

Olowo seun gbogbo tan

*** lomo abiola nko

Olowo seun gbogbo tan

Oba alhaja simi atinuke

Olowo seun gbogbo tan

Oko tunde raji olayinka

Olowo seun gbogbo tan

Oko *** adeebisi

Emasa ema soro leyin

Olowo seun gbogbo tan

Afeimi jara bi ajere

Olowo seun gbogbo tan

Gbajumo ara to jeun ajumo asa 2x


Instrumentals


Abiola ko’le lowo wa

Ore eda to ba wa debe lo le so

Ile na wa dabi afin oba

Kiku ma p’abiola o

K’arun ma s’abiola o

L’aye

Kiku ma p’abiola o

K’arun ma s’abiola o

L’aye e dowo o

Eh he

Koba ma doju ti e o

Laiye

Abi abi abi-ola

Ka gbadura

Baba kudirat omolola ose

Abi ola ka gbadura

Baba kolawale o

Baba Samson o

Baba gunola

Abi ola

Ka gbadura

Onitemi o

Baba semiatu

Abi ola

Ka gbadura

***

Abi ola

Ka gbadura

Baba olalekan olaronke

Abi ola

Ka gbadura

***

Abi ola

Ka gbadura

Baba abiodun mi atata

Abi ola

Ka gbadura

Baba oladudu mi agbagba

Abi ola

Ka gbadura


Instrumentals


I love my darling

My darling loves me

No circumstances

Can change my opinion

I love my darling

My darling loves me

No circumstances

Can change my opinion


Emama se

Emama danwo

Igba ope arami ma danwo

Emama se emama danwo

Igba ope arami ma danwo

Awon eda kan lowa

Tiwon majomolomo je

Awon eda kan lowa

Tiwon majomolomo je

Won ni won ke

Iyen nise tiwon

Tan ba ri t’oko t’aya

Tiwon feran ara won

Tan ba ri t’oko t’aya

Tiwon feran ara won

Won ma wero lati won tu won ka

Ti o ba sese fun won

Won wa idi miran

Won ma bere isokuso

Won ni won ke

Iyen nise tiwon

Ara lon t’awon

Ori won ni o fe jo

My dear

Ma ma dawon loun


Mo mo kolawole kan

Oko olubunmi o

Olokodana lounje

***

Mo mo kolawole kan

Oko olubunmi o

Olokodana lounje

E pe kolawole kin gbo

Kola kolawole

Efi xxx kin gbo

Kola kolawole

Ayinla baba farouk pe kin gbo

Kola kolawole

xxx

Kola kolawole

xxx

Kola kolawole

Kola wole mi baba

***

Kola wole mi baba

***

Kola wole mi baba

Ajiwo kutu soro kan simileti

Ebi mi kilo tinwi

Oni kelekele ekun

T’ojo kan

kelekele ekun

T’ojo kan

Aisile ekun

L’aja gbo

Aisile ekun

Aja gbo

Aja to ri koko

Ton gbo

Aja to ri koko

Ton gbo

Esu ose koko 2x

Se aja lesu se

T’omo kayako

Ajiro tutu kefi gbajumo 2x

Omo are musulumi

Gbedu olola

Ajiro tutu kefi gbajumo

***

Ajiro tutu kefi gbajumo

***

Ajiro tutu kefi gbajumo

***

Ajiro tutu kefi gbajumo

More Lyrics from Chief Commander Ebenezer Obey Songs

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status