- Genre:Juju
- Year of Release:1972
Lyrics
Iwo lolufe mi
Sun mo mi fa mo mi
Ka so wo po
K’ole lo
Iwo lolufe mi
Sun mo mi fa mo mi
Ka so wo po
K’ole lo
Ijo lebi emi o
Kirini iti o
Ka so wo po
K’ole lo
Oro ajo so wa
Dakun ma ma so sita
Ka so wo po
K’ole da
B’ogiri o l’anu o
Alangba o le raiye wo ogiri
Ka so wo po
K’ole da
Oro ajo so wa
Dakun ma ma so si ta
Ka so wo po
K’ole da
Ilo si waju oko
O’nbe o lowo aya rere
Ka so wo po
Ko le da
Ilo si waju aya
O’nbe o lowo oko rere
Ka so wo po
Ko le da
Etu eko se Pataki
Fun omo ti aba bi
Ka so wo po
Ko le da
Nitori kiya ma je won
Leyin wa ola
Ka so wo po
Ko le da
Ijo lebi eni o
Iri ini ti o
Ka so wo po
Ko le da
Oro ajo so wa
Dakun ma ma so si ta
Ka so wo po
K’ole da
B’ogiri o l’anu o
Alangba o le raiye wo ogiri
Ka so wo po
K’ole da
Uhun owo otun se losi owa
Dakun yeyi o aya mi
Ka so wo po
K’ole da
Instrumentals
Oro kan ni mo fe bi yin
Eyin eniyan
International brothers
Eba mi da si
Oro kan ni mo fe bi yin
Eyin eniyan
International brothers
Eba mi da si
Ani ninu obi eni
Pelu aiya eni
Ewo lo se Pataki
To se koko
Chief commander
Ese adupe
A o gbodo fowo obi we
T’aya eni
A o gbodo fo’ro iyawo we
T’obi eni
A o gbodo f’oro obi we
T’aya eni
A o gbodo f’oro aya we
T’obi eni
Oun obi le se
Iyawo ole se yen
Oun ti iyawo le se
Obi o le se yen
Amo ka lo ranti pe
Aya le yani
Iyawo le kan ni
Ipo kipo ta wa
L’ojo jije
L’ojo airi je
Ninu igbadun
Abi l’ojo isoro
Obi eni o le boni
Iya mi o
Iya mi o
Iya la l’abaru
Iya mi o
Iya mi o
Iya la l’abaru
Iya t’omu mi dagba
Iya t’obi mi saiye
Iya mi o
Iya mi o
Iya la l’abaru
Mama t’omu mi dagba
Mama t’obi mi saiye
Iya mi o
Iya mi o
Iya la l’abaru
Agbo mo dani
Afe se p’ale
Logojo oru
Iya mi o
Iya mi o
Iya la l’abaru
Agbeni dani
Afe se p’ale
Logojo oru
Iya mi o
Iya mi o
Iya la l’abaru
Agbo mo dani
Afe se p’ale
Logojo oru
Iya mi o
Iya mi o
Iya la l’abaru
Instrumentals
Ko ye ko po si bikan
B’awon okunrin ba ti so tiwa
Oremi oye ka ma ranti
Gbogbo awon obinrin
Oro kan ni mo fe bi yin
Eyin eniyan
International brothers
Eba mi da si
Oro kan ni mo fe bi yin
Eyin eniyan
International brothers
Eba mi da si
Ani ninu obi eni
Pelu oko eni
Ewo lo se Pataki
To se koko
Chief commander
Ese adupe
A o gbodo fowo obi we
T’oko eni
A o gbodo f’oro oko we
T’obi eni
A o gbodo f’oro obi we
T’oko eni
A o gbodo fowo oko we
T’obi eni
Oun tobi le se
Oko ole se yen
Oun ti Oko le se
Obi o le se yen
Amo ka lo ranti pe
Oko le ko ni
Baale le ni
Ipo kipo ta wa
L’ojo jije
L’ojo airi je
Ninu igbadun
Abi l’ojo isoro
Obi eni o le ko ni
Instrumentals
Iya mi iya
Iya la l’abaru
Iya mi iya
Iya la l’abaru
Iya mi iya o
Iya la l’abaru
Iya mi iya
Iya la l’abaru
Iya mi iya
Iya la l’abaru
Iya o 10x
Instrumentals
Mele gbagbe omo oloye
Sidney olatubosun mi o
Oko alhaja ibidun en le ose
Omo bameke
Ibadan sha ile oluyole omo ni
Mele gbagbe kayode amodun
Kayode amodun mi o
En le oyinbo alaso
S’omo ru e
Ere ni
S’omo ru e
Ere ni
Ere 2x
Ere ere
Ere ni
Esu lo s’omo agutan
To duro wo koko loju
Esu lo s’omo agutan
To duro wo koko loju
Ati duro gugi duro gugi
Ati bere gugi bere gugi
Ati gungi opolo seju ejo ni ose
Esu lo s’omo agutan
To duro wo koko loju
Ori eye ni o peye
Ori eye ni o peye
Ori eye ni o peye
Ori eye ni o peye
Iho to wo aparo
Bi tabi dola
Ori eye ni o peye ah
Esu lo s’omo agutan
To duro wo koko loju
Taba be egungun egungun agbo
Taba be orisa orisa agba
Ti a ba be orun oba darijini ah
Esu lo s’omo agutan
To duro wo koko loju
Ori eni l’an wure o
Eda lalayo mo
Mau meke o
Kososi loro e
Ori eni l’an wure o
Eda lalayo mo
Mau meke o
Kososi loro e