To Ba Je Tere Lyrics
- Genre:Juju
- Year of Release:1987
Lyrics
To ba je tere
Ati wa latise
To ba je tijo
Ke mu ra lati jo
Keyin onilu mi filu si
Kefeyi toku sile lodo mi
To ba je tere
Ati wa latise
To ba je tijo
Ke mu ra lati jo
Keyin onilu mi filu si
Kefeyi toku sile lodo mi
To ba je tere
Ati wa latise
To ba je tijo
Ke mu ra lati jo
Keyin onilu mi filu si
Kefeyi toku sile lodo mi
To ba je tere
Ati wa latise
To ba je tijo
Ke mu ra lati jo
Keyin onilu mi filu si
Kefeyi toku sile lodo mi
Instrumentals
Oro mi dori o dori
O dori omo binrin
Pelu omo kunrin kan
Tiwon jo gbara won
Oro mi dori o dori
O dori omo binrin
Pelu omo kunrin kan
Tiwon jo gbara won
Won mura tan lati se iyawo
Baby ba ni a lo
Won mura tan lati se iyawo
Baby ba ni a lo
T’ojo lowo
T’ojo lola
To ni moto repete
Sisi olorun sogo
Elele
Lai fara gun
Boro ba doju ru
Sisi ba ni lo ni a lo
Ara ile be baby ti ti
Sisi Odale
O ba ni lo ni a lo
Ara adugbo be baby ti ti
Sisi Odale
O ba ni lo ni a lo
Ebi oko be baby ti ti
Sisi Odale
O ba ni lo ni a lo
Mase gbara lobirin o
Mase gbara dobirin odale
Mase gbara lobirin o
Mase gbara dobirin odale
Nigba ikanju won da e si le
Won wa sofun e pe
Iru e simi
Iru mi si e
Ta bo roye
Asa kin fe e
Maya folowo lo o e
Instrumentals
Odo omo binrin yi o more
Odo omo binrin yi o more
Odo omo kunrin o tenu morin
Oni odo omo binrin yi o more
Odo omo binrin yi o more
Owo ko ni gbogbo nko
Odo omo binrin yi o more
Owo ko ni gbogbo nko
Odo omo binrin yi o more
Oro yi ka omo kunrin lara
Owo ke titi
O fese jo le
Oro yi ka omo kunrin lara
Owo ke titi
Ofese jo le
Oun ni ore nla
Ni kalaya sile
Ta ba laya sile
To ba bimo fun ni
Bi o ba si tomo
Bobirin ba ko ni
Wahala lo ko ni
Iya mi ko, iwo ke
Mase gbara lobirin o
Mase gbara dobirin odale
Mase gbara lobirin o
Mase gbara dobirin odale
Nigba ikanju won da e si le
Won wa sofun e pe
Iru e simi
Iru mi si e
Ta bo roye
Asa kin fe e
Maya folowo lo o e
Emi si e
Iwo sopo wire
Omo kunrin be sisi titi
Sisi Odale
O ba ni lo ni a lo
Ore oko be baby titi
Sisi Odale
O ba ni lo ni a lo
Ebi oko kowe si sisi
Sisi Odale
O ba ni lo ni a lo
Aseyinwa aseyin bo
Bi oniya
Won jade bi si e
Otun belomiran lo
Kiran kita to nbe
Alaseju gbomilo
Kiran kita to nbe
Alaseju gbomilo
Kiran kita to nbe
Alaseju gbomilo
Kiran kita to nbe
Alaseju gbomilo
Biwon ba so falaseju
Ko ni gbo
Kiran kita to nbe
Alaseju gbomilo
Ti won ba so falaseju
A ta ku
Kiran kita to nbe
Alaseju gbomilo
Ti won ba so falaseju
A ta ku
Kiran kita to nbe
Alaseju gbomilo
Instrumentals
Kayode omo faloye 2x
Kayode o oko iyabo o
Kayode o oko iyabode
Kayode 3x
Kayode omo faloye 2x
Kayode o oko iyabo o
Kayode o oko iyabode
Kayode 3x
Akure nile
Hmm oloye mekun
Ile kayode o
O oloye mekun
Akure nile
Hmm oloye mekun
Ile kayode o
O oloye mekun
Ben carson o ose
Chief kayode mi omo faloye
Oko iyabode dele
Baba ademola
Baba ronke ronke
Baba jemi ekijimi
Baba segun aja segun
Baba kunle o kunle
*** omo faloye
Ema ale mo kayode mi
Kin lenikan se tenikan ose ri
Kin lenikan se tenikan ose ri
Ema ale mo kayode mi
Oko iyabode oko dele
Ema ale mo kayode mi
Ema ale mo kayode mi
Ben caf
Ema ale mo kayode mi ah
Kin lenikan se tenikan ose ri
Kin lenikan se tenikan ose ri
Ema ale mo kayode mi
Kayode faloye mi akure
Ko seni to le yara si e
Ko ma jiya
Ko seni to le yara si e
Ko ma jiya
Ko seni to le yara si e
Ko ma jiya
Ko seni to le yara si e
Ko ma jiya
Ko seni to le yara si e
Ko ma jiya
Ko seni to le yara si e
Ko ma jiya
Ko seni to le yara si e
Ko ma jiya
Ko seni to le yara si e
Ko ma jiya
Kayode kayode
Omo faloye
Kayode kayode
Omo faloye
Kayode l’akure o
Omo faloye
Kayode kayode
Omo faloye
Oko iyabode
Oko dele mi o
Kayode kayode
Omo faloye
***