Loading...

Download
  • Genre:Juju
  • Year of Release:1973

Lyrics

Sikisiki mami

Owo wole de

Oowo oo owo le soun gbogbo

Sikisiki mami

Owo wole de

Oowo oo owo le soun gbogbo


Olomo lo l’aye are mi o

Omo larowon ere

Olomo lolaye olomo lolaye

Aiye o omo laso

Olomo lo l’aye ore mi o

Omo larowon ere

Olomo lolaye olomo lolaye

Aiye o omo laso


Baba fun won laisiki otun o

Karowofun saye

Olowoloye olowoloye

Owo le seun ongbogbo

Baba fun won laisiki otun o

Karowofun saye

Olowoloye olowoloye

Owo le seun ongbogbo


Olomo lo l’aye are mi o

Omo larowon ere

Olomo lolaye olomo lolaye

Aiye o omo laso


Aimo asiko lo damu eda o

Ayanmo onikalukuu

Odaju koni da se

Aimo asiko lo damu eda o

Ayanmo onikalukuu

Odaju koni da se


Aimo asiko lo gbamu eda o

Ayanmo onikalukuu

Odaju koni da se

Aimo asiko lo gbamu eda o

Ayanmo onikalukuu

Odaju koni da se


Ani bi osi temi

Ore oni leje

Ye o bi osi temi

Ore oni le mu

E jo wo e ma sobe mo

Oba oluwa l’alewiyese


Ye o bi osi temi

Ore oni leje

Ani bi osi temi

Ore oni le mu

E jo woe ma sobe mo

Oba oluwa l’alewiyese


Eda to sope ko si iru hun o

E sofun pe iro lonpa

Iru e da wa o

Iru oluwa ni o si

Iru eda wa

Eda gan e mare dakun o

Eda to sope ko si iru hun o

E sofun pe iro lonpa

Iru e da wa o

Iru oluwa ni o si

Iru eda wa

Eda gan e mare dakun o


Awon eda kan lowa

Tan fe kenikejije

Awon eda kan lowa

Tan fe kenikejije


Eri kan je mirokun

Ogbowo doluwa

Otun fi moniya

Ile ise e

Aimoye eniyan

Ti won je ti won mu


Instrumentals


Eri faje mirokun

Ogbowo doluwa

Otun fi moniya

Ile ise e

Aimoye eniyan

Ti won je ti won mu


Aya feyan lasan

Lole soro enibi

Faje mirokun

Odidi aje bi eleda

Aya feyan lasan

Lole soro enibi

Kose falejo

Ose fonile

Aya feyan lasan

Lole soro enibi

***

Aya feyan lasan

Lole soro enibi

***

Aya feyan lasan

Lole soro enibi

***

Aya feyan lasan

Lole soro enibi

***

Aya feyan lasan

Lole soro enibi

***

Aya feyan lasan

Lole soro enibi

Eje o gbaye

Eje o gbaye faje mirokun

Eje o gbaye 2x

Eje o gbaye faje mirokun

Eje o gbaye 2x

Eje o gbaye faje mirokun le

Iku oni pa e o

Faje mirokun

Arun oni se o

Faje mirokun

Onitemi o eje o gbaye 3x

Eje o gbaye faje mirokun

Leta t’oluwa bako

Ko seda to le yi pada

Je jeri loro e

Leta t’oluwa bako

Ko seda to le yi pada

Je jeri loro e


Leta t’oluwa bako

Ko seni to le yi pada

Je pari loro e

Leta t’oluwa bako

Ko seni to le yi pada

Je pari loro e


Mo wa tara sasa

Odile oluyole mi o e

Chieh high s omo adewale

Chief osigba o

High chief of lagos

Adewale olola

The boy is good ni

Odile gbajumo

Omo adewale

Eni adewale

Ola adewale

Eni adewale

Ola adewale

Adewale omo gbajumo

Ni ogboro eko

Adewale omo oloye

Ni isale ofin

Ol’oyinbo ni ofe

Alayan ni ofe memo


Isale ofin o laiye 5x

Se awon lo lode

Se awon ma tule

Isale ofin

E simi agbagba ose

Olo n mawu mawu

Isale ofin isale ofin

Oru mawu mawu

Ofin ofin o

Oru mawu mawu

High s omo adewale

Oru mawu mawu

Isale ofin isale ofin

Oru mawu mawu

The boys idoje

Oru mawu mawu

Ofin ofin o

Oru mawu mawu

Isale ofin isale ofin

Oru mawu mawu

***

Oru mawu mawu

***

Oru mawu mawu

High s omo adewale

Oru mawu mawu

Chief achigba o

Oru mawu mawu


Kiku ma padewale o

Tiwa

Karun ma s’adewale o

Owo aiye koni te e o

Tiwa

Asun gbagbe koni kan e o

Adewale o baba lode 2x

***

Adewale o baba lode

***

Adewale o baba lode

***

Adewale o baba lode

***

Adewale o baba lode


Eleganza elezance

Eleganza omo okoya

Eleganza elezance

Eleganza omo okoya

Eleganza o elezance

Eleganza omo okoya

Adura sakiri omo okoya

For quality

For the best jewelries

Eleganza is the best for you

For quality

For the best jewelries

Eleganza is the best for you


Okun eko wun mi lo o 2x

Mo lo mori eleganza

Okun eko wun mi lo o

Adura sami o


Eleganza lo gbayi omo okoya 2x

Sonile adu rasaki

Omo okoya

Okun eko wun mi lo o

Yeri eti egba owo

Lo ba mi se

Eleganza lo gbayi omo okoya

Egba owo

O dara biye ni

Eleganza lo gbayi omo okoya

Pelo oruka o

O dara julo

Eleganza lo gbayi omo okoya

Eleganza mi o omo okoya

Eleganza lo gbayi omo okoya

More Lyrics from Chief Commander Ebenezer Obey Songs

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status