Loading...

Download
  • Genre:Gospel
  • Year of Release:2013

Lyrics

Moti gbe oluwa ga

Niwaju mi

Nigba gbogbo

Ko s’ogun aye kan

To le bori okan mi

Nitori odaju pe

Oluwa nbe ni atiwa

Asegun niwa

Nipa eje re


Ayigbagbo bila

Temi l’oluwa

Mo mo oun yio si dide

Fun igbala mi

Kin sha ma gbadura

Oun o se iranwo

Gba kristi wa lodo mi

Ifoya kosi


Ayigbagbo bila

Temi l’oluwa

Mo mo oun yio si dide

Fun igbala mi

Kin sha ma gbadura

Oun o se iranwo

Gba kristi wa lodo mi

Ifoya kosi


Moti gbe oluwa ga

Niwaju mi

Nigba gbogbo

Ko s’ogun aye kan

Ko s’ogun aye kan

To le bori okan mi

Nitori pe

Nitori odaju pe

Oluwa nbe ni atiwa

Asegun ni mo je

Asegun niwa

Nipa eje re


Bono mi ba shu

Oun lo shan to mi

Kemi sha ti gboran

Oun o si pese

Bi iranwo eda

Gbogbo sha ki

Oro tenu jesu so

Ni yio bori

Ife to fi han mi

Lo je kin mo pe

Jesu kole fi mi sile

Ninu wahala

E iranwo ti mosi ri

Lojojumo

O ki mi laya pe

Emi yio la ja


Moti gbe oluwa ga

Moti gbe

Niwaju mi

Nigba gbogbo

Nigba gbogbo

Ko s’ogun aye kan

To le bori okan mi

Nitori odaju pe

Oluwa nbe ni atiwa

Jesu wa fun mi o

Asegun niwa

Nipa eje re


Emi o wa se kun

Tori iponju

Tabi irora oti so tele

Mo mo oro re pe

Awon ajogun igbala

Won ko le shalayi koja

Laarin wahala

Sugbon igba kristi wa lodo mi

Ifoya kosi

Gba kristi wa nipin temi

Asegun mo je

Eda ko le royin

Kikoro agan

T’olugbala mu

K’elese le ye

Aye re tile buru

Ju temi lo

Jesu mi a le jiya

Kemi si ma sa


Moti gbe oluwa ga

Niwaju mi

Nigba gbogbo

Ko s’ogun aye kan

To le bori okan mi

Nitori odaju pe

Oluwa nbe ni atiwa

Asegun niwa

Nipa eje re


Nje boun gbogbo

Tin sise ire

Fun awon to duro de

Duro de oluwa

Boni tile koro

Sha koni pe mo

Gbano orin isegun

Bi oti dun to

Satani le ale

Jesu wa fun mi

Oduro timi leyin

Bi akoni eleru


Moti gbe oluwa ga

Niwaju mi

Nigba gbogbo

Ko s’ogun aye kan

To le bori okan mi

Nitori pe o dami loju

Nitori odaju pe

Oluwa nbe ni atiwa

Asegun niwa

Nipa eje re


Moti gbe oluwa ga

Niwaju mi

Nigba gbogbo

On be niwaju mi

Ko s’ogun aye kan

To le bori okan mi

Nitori odaju pe

Oluwa nbe ni atiwa

Asegun niwa

Nipa eje re

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status