Loading...

Download
  • Genre:Gospel
  • Year of Release:2014

Lyrics

Oju re ni mo wo oluwa

Ma ma

Wa mi ti o

Oju re ni mo wo oluwa

Ma ma

Wa mi ti o

Si o

E re ni mo gboju mi soke si

Oluwa iwo ni fi okan mi le

Ogun aye yi le

Ole la leju baba

Ma ma

Wa mi ti o


Iwo loba to s’eda oun gbogbo

Iwo loba ti gbogbo aye sa to

Oro aye mi dowo re eledumare oba

Ma ma

Wa mi ti o


Oro no ni nkankan to fi

Soro jabesi dayo

Iseti aso re lo wo

Eje odun mejila

O se ti hannah

O fun hannah lorin tuntun ko

O se ti sarah

Nigba taye rope oti pari

Agbara ko yi pada

O wa sibe titi lai

Ma ma

Wa mi ti o


Egan ton be laye mi yi

Oti fe di isonu

Oti fe mu kaye bere pe

Olorun mi da

Awon agan won woju re

Awon onirobinuje nke si o

Baba ma pawon ti

Shiju anu wo won

Ko seti sha l’oruko re

Fun won lerin ayo

Je ko gbegba ope

Oju re ni mo wo oluwa

Ma ma

Wa mi ti o


Oba toni kokoro agbara

Wa shilekun fun mi o

Oba toni kokoro agbara

Wa shilekun fun mi o

Oba toni kokoro agbara

Wa shilekun fun mi o

Oba toni kokoro agbara

Wa shilekun fun mi o


Ilekun to ti ti

Baba bami shi

Ogo to ti nu

Baba bami wa

Ilekun to ti ti

Baba bami shi

Ogo to ti nu

Baba bami wa


Oba toni kokoro agbara

Wa shilekun fun mi o

Oba toni kokoro agbara

Wa shilekun fun mi o

Wa bami shi baba

Oba toni kokoro agbara

Oluwa

Wa shilekun fun mi o

Oba toni kokoro agbara

Wa shilekun fun mi o


Ilekun to ti ti

Baba bami shi

Ogo to ti nu

Baba bami wa

Ilekun to ti ti

Baba bami shi

Ogo to ti nu

Baba bami wa


Olorun toni kokoro agbara

Mogbe aye mi to o wa

Baba to ni kokoro gbogbo agbara

Aye mi re

Olorun toni kokoro agbara

Mo gbe aye mi to o wa

Baba to ni kokoro gbogbo agbara

Aye mi re

Ile kun to ba ti

Kosi eni to le shi

Ile to ba shi

Ko seni to le ti

Aye to ba tunse

Kosi eni to le baje mo

Wa tun aye mi se

Wa numije mi nu

Wa sekun mi derin

Wa mu igba yi lo o

Wa mu igba to dun wa

Wa numije mi nu

Wa sekun mi derin

Wa mu igba yi lo o

Wa mu igba to dun wa


Oba toni kokoro agbara

Wa shilekun fun mi o

Oba toni kokoro agbara

Wa bami shi

Wa shilekun fun mi o

Oba toni kokoro agbara

Oluwa

Wa shilekun fun mi o

Oba toni kokoro agbara

Wa shilekun fun mi o


Ilekun to ti ti

Baba bami shi

Ogo to ti nu

Baba bami wa

Ilekun to ti ti

Baba bami shi

Ogo to ti nu

Baba bami wa


Iwo lo da ikolo sioni pada o

To dabi eni tin lala

Oyi igba jabesi pada o

O fun jabesi l’oruko tuntun

Obinrin orisun eje nko

O fowo kan iseti aso re

Ori iwosan kuro ninu ayisan

Orisun eje odun mejila

Egan yi ti to

Abuku yi ti to

E shanu fun mi o

Pamilerin ayo

Fun mi ni eri

Ninu odun yi o baba

Pamilerin ayo

Fun mi ni eri

Ninu odun yi o baba


Oba toni kokoro agbara

Olorun to ni kokoro gbogbo agbara

Wa shilekun fun mi o

Oba toni kokoro agbara

Wa shilekun fun mi o

Oba toni kokoro agbara

Wa shilekun fun mi o

Oba toni kokoro agbara

Wa shilekun fun mi o


Ilekun to ti ti

Baba bami shi

Ogo to ti nu

Baba bami wa

Ilekun to ti ti

Baba bami shi

Ogo to ti nu

Baba bami wa


Iwo ni mo ke pe oluwa

Wa fi opin si ibanuje mi

Iwo ni mo ke pe oluwa

Wa f’opin si ibanuje mi

O so owon dopo ni samaria

Ko soun to le se

Eni taye sope ko le bimo

O pada wa di iya ibeji

Eni taye sope kole je

Nkankan

O t’ori akintan wa joba

Oriburuke ya gberu e

Asedanu kuro laye mi

Ibanuje o shoshu yi ti to

Promise and fail otoge

Mo duro lori kristi apata

Ile miran iyanrin ni

Mowa diro mo agbelebu

Mo pase loruko jesu

Le jade o kuro laye mi

Oya baba ti won jade o

Oya baba ti won jade

Oya baba ti won jade o


Oba toni kokoro agbara

Olorun

Wa shilekun fun mi o

Oba toni kokoro agbara

Wa shilekun fun mi o

Oba toni kokoro agbara

Wa shilekun fun mi o

Oba toni kokoro agbara

Wa shilekun fun mi o


Ilekun to ti ti

Baba bami shi

Ogo to ti nu

Baba bami wa

Ilekun to ti ti

Baba bami shi

Ogo to ti nu

Baba bami wa


Oba toni kokoro agbara

Olorun

Wa shilekun fun mi o

Oba toni kokoro agbara

Wa shilekun fun mi o

Oba toni kokoro agbara

Wa shilekun fun mi o

Oba toni kokoro agbara

Wa shilekun fun mi o


Ilekun to ti ti

Baba bami shi

Ogo to ti nu

Baba bami wa

Ilekun to ota ti

Baba bami shi

Ogo to ti nu

Baba bami wa

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status