Loading...

Download
  • Genre:Afrobeats
  • Year of Release:2014

Lyrics

Igba Sa Lonigba Nlo - Evang. Ojo Ade

...

Igba sa l'onigba n lo, asiko si ni gbogbo nkan l'aye

L'orukô Jesu ômô Ôlôrun, igba t'emi ko ni k'ôja mi

Ma gbe'nu ôrô wa f'aini p'itan o, orin ôpê o a gb'ęnu mi kan

Igba sa l'onigba n lo, asiko si ni gbogbo nkan l'aye

L'orukô Jesu ômô Ôlôrun, igba t'emi ko ni k'ôja mi

Ma gbe'nu ôrô wa f'aini p'itan, orin ôpê o a gb'ęnu mi kan

Ôrê gbô ôrô Ôlôrun

B'ękun pę d'alę kan

Ayô nbô l'owurô

Lai si ogun, ara mi, eniyan kan ko le d'asęgun

Ninu adura igba gbogbo

Lai ręwęsi

Isęgun daju

Ibanuję rę a d'ohun itan o, Halleluyah a gb'ęnu rę kan

Igba sa l'onigba n lo, asiko si ni gbogbo nkan l'aye

L'orukô Jesu ômô Ôlôrun, igba t'emi ko ni k'ôja mi

Ma gbe'nu ôrô wa f'aini p'itan, orin ôpê o a gb'ęnu mi kan

Iwô baba f'ôkan balę, Arabinrin o lô t'ujuka

Awôn isoro ninu, l'ode eyi t'o n d'oju k'ôkan rę

O ro titi aye su ô, dię lo ku, wa laaja

Ibanuję rę a d'ohun igbagbe, orin iyin a gb'ęnu rę kan

Igba sa l'onigba n lo, asiko si ni gbogbo nkan l'aye

L'orukô Jesu ômô Ôlôrun, igba t'emi ko ni k'ôja mi

Ma gbe'nu ôrô wa f'aini p'itan, orin ôpê o a gb'ęnu mi kan

Awôn isoro aye rę, o le koko bi irin o

Ati sanwo ile ogun, jiję, mimu inira l'oję

Gbogbo aso pata lo ti śa, ati ramiran ko si r'ôrun

Mo wi fun ô, o ni ra si

Sa ma gb'adura, ogun rę a sę

Osi at'are a d'ohun igbagbe, Halleluyah a gb'ęnu rę kan

Igba sa l'onigba n lo, asiko si ni gbogbo nkan l'aye

L'orukô Jesu ômô Ôlôrun, igba t'emi ko ni k'ôja mi

Ma gbe'nu ôrô wa f'aini p'itan, orin ôpê o a gb'ęnu mi kan

Ękun, ose mi a d'opin o (Halleluyah a gb'ęnu mi kan)

Iwô agan wa yô l'ôdun yi o (Halleluyah a gb'ęnu rę kan)

Alaisan yi, o ma ni ra si (Orin ôpê o a gb'ęnu rę)

Alaini wa l'aluyo o (L'orukô Jesu, ninu ôdun yi)

Iwô aboyun wa sô l'ayô (Halleluyah a gb'ęnu rę kan)

Onisowo wa j'ere l'aye (Orin ôpê o a gb'ęnu rę kan)

Onise ijoba wa gba 'gbega (Halleluyah a gb'ęnu rę)

Ômô ile-iwe wa s'aseyôri o (Orin ôpê o a gb'ęnu rę)

Gbogbo ęyin t'ę n gbô mi o (Halleluyah a d'orin awa)

Gbogbo ęyin t'ę t'ęti si mi o (Halleluyah a d'orin awa)

Igba sa l'onigba n lo, asiko si ni gbogbo nkan l'aye

L'orukô Jesu ômô Ôlôrun, igba t'emi ko ni k'ôja mi

Ma gbe'nu ôrô wa f'aini p'itan, orin ôpê o a gb'ęnu mi kan

Igba sa l'onigba n lo, asiko si ni gbogbo nkan l'aye

L'orukô Jesu ômô Ôlôrun, igba t'emi ko ni k'ôja mi

Ma gbe'nu ôrô wa f'aini p'itan, orin ôpê o a gb'ęnu mi kan

Similar Songs

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status