Loading...

Download
  • Genre:Afrobeats
  • Year of Release:2018

Lyrics

Iwo Naa Riri - Evang. Akintunde Obasemilogo

...

Lyric by Willicino please follow me


Oluwa o to akoko ki o gbe mi ga

oluwa o to akoko ki o gbe mi ga

ojo nlo Lori mi o igba koduro

from story to glory je ki itan mi dogo oo

Ani ke mi naa foshii pitan ninu ogo oo


chorus: Oluwa oti akoko ki o gbe mi ga

Oluwa oti akoko ki o gbe mi ga

Ojo nlo Lori mi o igba koduro

From story to glory je ki itan mi

dogo oo

Ani ki emi naa foshii pitan ninu

ninu ogo ooooo

Ojo Ori mi nlo o bi ala ti a un la

igba mhi n tan lo Lori le olorun Sha nu mi

idi to de mi de ohun gbogbo ko rojo Ori de

oluwa se oma wo mi niran no

Tete gbami o ojo ma fi akoko mi so fo

from to glory je ki itan mi dogo oo

Ani ki emi naa foshii pitan ninu ogo oo


chorus: Oluwa oti akoko ki o gbe mi ga

Oluwa oti akoko ki o gbe mi ga

Ojo nlo Lori mi o igba koduro

From story to glory je ki itan mi

dogo oo

Ani ki emi naa foshii pitan ninu

ninu ogo ooooo

ijile ni o olorun bami kajogbola

eni o ba Sanu lo goke agbara naa

iwo lo shanu kajogbala temi nko?

emi nu ni itan to Koro bi dapa

itan to bere pelu ikoro ati iponju nla

odi gba to ba pari sinu ogo oo Kaye o to gbo

from story to glory jeki itan mi dogo oo

Ani ki emi naa foshii pitan ninu ogo oo


chorus: Oluwa oti akoko ki o gbe mi ga

Oluwa oti akoko ki o gbe mi ga

Ojo nlo Lori mi o igba koduro

From story to glory je ki itan mi

dogo oo

Ani ki emi naa foshii pitan ninu

ninu ogo ooooo

Angeli to jise Ayo o do mi ni a ran o si

o gi se ayo fun dilekan itan dogo oo

ile mi lo kan mo fe ri oo


chorus: Angeli to n jise ayo odo mi

ni a ran o si

o gi se ayo fun idile kan

itan dogo oo ile mi lo kan

no fe ri oo

Angeli kan n be ni waju baba Gabrieli ni

ohun la fi ran lati pi ire ayo Kiri

to ba ti ja de ile to ba de o ma da layo

ile mi lo kan mo fe ri oo


chorus: Angeli to n jise ayo odo mi

ni a ran o si

o gi se ayo fun idile kan

itan dogo oo ile mi lo kan

no fe ri oo

O ma tete oo angeli mi

to ba de itan mi a do pin

oju ogbe ibanuje be Lara mi

wa ba mi bu ororo ayo si

oti se fun Maria ati Elizabeti lo jo si

ile mi lo kan mo fe ri oo

angeli ma bo o


chorus: Angeli to n jise ayo odo mi

ni a ran o si

o gi se ayo fun idile kan

itan dogo oo ile mi lo kan

no fe ri oo

Abrahamu gba o la le jo(ninu bibeli mimo)

leyi eyi loto romo gbe jo

Aya Emmanueli gba la le jo

o bi Samsoni alagbara

isaaki gba o la le jo

egan ijo si yen o pa re

ko se ni ri o ti ko ra mi o

ile mi lo kan mo fe ri oo


chorus: Angeli to n jise ayo odo mi

ni a ran o si

o gi se ayo fun idile kan

itan dogo oo ile mi lo kan

no fe ri oo


Angeli to n jise ayo odo mi

ni a ran o si

o gi se ayo fun idile kan

itan dogo oo ile mi lo kan

no fe ri oo

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status