Ahon ati Eyin
- Genre:R&B
- Year of Release:2022
Lyrics
Ahon ati Eyin - DAVID OLURINDE
...
Lowo yii, ife wa dara Ko n shey gbogbo gba ni nkan mandun Mofe ko ranti ife yii, tiba sheshi ba eh nu je Darijin mi, eleran ara nimi Miole momo ja e kule(lai lai) Miole didi gbomije loju re laiye laiye Ahon ati eyin ja Amo won di ore pada Maje ki asishe me di ogun, ko maba arin wa je Ki nkan tagbin toun wu Oni latiri ojo ati orun, Gbogbo wa lamo, ko se ni to mo ola Asiko to n da, awa nikan loye Asiko to n dun, awa nikan lamo Tija bade larinwa, maje kan gbo ladugbo Ogiri wa, kogbodo lanu Miole momo ja e kule, laiye laiye Miole didi gbomije loju re, laiye laiye Ahon ati eyin ja Amo won di ore pada Maje ki asishe me di ogun, ko maba arin wa je Ki nkan tagbin toun wu Oni latiri ojo ati orun Gbogbo wa lamo, ko se ni to mo ola Ahon ati eyin ja Amo won di ore pada Maje ki asishe me di ogun, ko maba arin wa je Ki nkan tagbin toun wu Oni latiri ojo ati orun Gbogbo wa lamo, ko se ni to mo ola (hmmmm hmmmhmm)
Similar Songs
More from DAVID OLURINDE
Listen to DAVID OLURINDE Ahon ati Eyin MP3 song. Ahon ati Eyin song from album Yoruba demon is released in 2022. The duration of song is 00:02:41. The song is sung by DAVID OLURINDE.
Related Tags: Ahon ati Eyin, Ahon ati Eyin song, Ahon ati Eyin MP3 song, Ahon ati Eyin MP3, download Ahon ati Eyin song, Ahon ati Eyin song, Yoruba demon Ahon ati Eyin song, Ahon ati Eyin song by DAVID OLURINDE, Ahon ati Eyin song download, download Ahon ati Eyin MP3 song
Comments (1)
New Comments(1)
E2NU86
[0x1f623][0x1f623][0x1f623][0x1f623][0x1f623][0x1f623]