Loading...

Download
  • Genre:Gospel
  • Year of Release:2024

Lyrics

Jesu Mi - Tope Flourish

...

......... Jesu mi o, jesu mi o aanu rẹ lọn sogo lori aiye mi ofanu gbemi iyì rẹ rẹ ọ baba (jesu mi o) Jesu mi ọ jesu mi ọ aanu rẹ lọn sogo lori aiye mi (Anu ni morigba) ofanu gbemi iyì rẹ rẹ o baba Gbope ti mo muwa ọ jesu gba iyi timo muwa arojile ni moro ti mo ri wipe eti se pupo loro mi. Jésù mi o Jesu mi o ọrẹ ti kín koni sile alabarin tiki pa daa. Jésù mi o (Jesu mi mo ki ọ) jesu mi ọ (Aba ni gberu dori) aanu rẹ lọn sogo lori aiye mi ofanu gbemi iyì rẹ rẹ ọ baba Oloruko nla oloruko aperire iku oro re lọn somi d'ẹni igbala jesu olurapada mi ẹjẹ to ta sílẹ lọ gbami lowo egu ofi jesu eku Ise mi, iwo lapeke iwo lapeki eni ti oku gboruko re to palolọ iwo lapeki iwo lajike Isun ẹjẹ odun mejila gbe nipa aṣẹ rẹ Jésù mi o (oloruko aperire) jesu mi ọ (oloruko apetagiri) aanu rẹ lọn sogo lori aiye mi (gbogbo idile jeese) ofanu gbemi iyì rẹ ti o baba Aanu sogo lori idajo lọtọ on sogo lori aiye mi, Anu sogo lori idajo ọ lọtọ on sogo lori aiye mi oluwa sofun Mósè wipe emi yo sanu fun awọn tí èmi yo sanu fún lari awọn tori anu gba oka ki mo won ebami ki Jésù gbogbo agbaye Jésù mi o jesu mi ọ ah jesu mi ọ óo jesu mi ọ Jesu jesu jesu ese momore Jésù (jesu mi o) Jesu (jesu mi o) jesu (afeni lafe tan) ese momore ololufe aiye mi alabaro ọkan mi ore nigba ipọnju o ese momore Jésù (lover of my soul) Jesu (my sugar daddy) jesu ( iwoni mo gbega) ese momore (emi mama more o) Jésù (ọsẹ olore ọ) Jesu (olore kanka) jesu(abáni múlẹ madani) ese momore

Listen to Tope Flourish Jesu Mi MP3 song. Jesu Mi song from album Jesu Mi is released in 2024. The duration of song is 00:04:55. The song is sung by Tope Flourish.

Related Tags: Jesu Mi, Jesu Mi song, Jesu Mi MP3 song, Jesu Mi MP3, download Jesu Mi song, Jesu Mi song, Jesu Mi Jesu Mi song, Jesu Mi song by Tope Flourish, Jesu Mi song download, download Jesu Mi MP3 song

Comments (2)

0/500

    New Comments2

    AYANLEKE DABORAH

    ❤️❤️❤️

    Nigeria

    Ali Foluke

    more insight ma

    Nigeria

    +

        -   or   -

        -   or   -

        NG +234

            Please Select A Playlist

            Add New Playlist

            Share on

            Embed: Love & Light EP

            Custom Size :

            • Default
            • Desktop(300*600)
            • Mobile(300*250)

            Type :

            • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
            Get Boomplay Premium
            for
            Payment Method
            Pay With
              Review and pay
              Order Date
              Payment Method
              Due Today
              Flutterwave
                Subscription Successful

                Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

                Now you have access to all the features of Boomplay App.
                Payment Failed

                Please check your balance and then try again.

                You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
                Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
                Payment Processing...
                10 s

                Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

                Payment Processing
                Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
                About Order Status