- Genre:Fuji
- Year of Release:2023
Lyrics
Intervene - Bola Olufemi A.K.A Adebola Royal Mummy Juju
...
Bomode ba gegi nigbo Awon agba lo mobi toma resi 2x Eje a wo o Adebola Eje a wo o Ka foju sunukun wo Ko le re sibi todara. Bomode ba gegi nigbo Awon agba lo mobi toma resi Eje a wo Eje a wo Ka foju sunukun wo Ko le re sibi todara Adebola Royal ye mowi temi o eni tobaleti ko gbo Ko gboro enumi Toripe, agba ki wa loja Kori omo tuntun wo Agba kiwa loja Kori omo tuntun wo Ka foju sunukun wo Ko le sibi todara Ilu to loba to nijoye To loun alumoni lorisirisi Ilu to loba toni ijoye To loun alumoni lorisirisi Amo sibesibe Owo o lenu Omo eleran wa njegun Omo alaso wa nwakisa o Ilu o rogbo, ko si abo topeye o Amukun eru e wo Oke Len wo E o ri isale ni Adebola Royal ni mose korin wipe Bawa dasi o Bawa dasi o Edumare baba Bawa dasi o Orile ede wa o nfe atunse o Edumare baba Bawa dasi o Fowo to awon olori wa kan bawa tun orile ede yi se Edumare baba Bawa dasi o Bawa dasi o wa bawa dasi o Edumare baba Bawa dasi o
Similar Songs
More from Bola Olufemi A.K.A Adebola Royal Mummy Juju
Listen to Bola Olufemi A.K.A Adebola Royal Mummy Juju Intervene MP3 song. Intervene song from album Intervene is released in 2023. The duration of song is 00:03:57. The song is sung by Bola Olufemi A.K.A Adebola Royal Mummy Juju.
Related Tags: Intervene, Intervene song, Intervene MP3 song, Intervene MP3, download Intervene song, Intervene song, Intervene Intervene song, Intervene song by Bola Olufemi A.K.A Adebola Royal Mummy Juju, Intervene song download, download Intervene MP3 song