OhEmGee Yoruba Hymns Medley 3 Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2019
This song is not currently available in your region.
Lyrics
OhEmGee Yoruba Hymns Medley 3 - EmmaOMG
...
1. okan mi yo ninu oluwa
Tori oje iye funmi
Ohun re dun pupo lati gbo
Adun ni lati roju re
Chrs: Emi yo ninu re, emi yo ninu re
Gba gbogbo lofi ayo kun Okan mi
Tori emi yo ninu re.
2. Otipe to ti nwa mi kiri
Gbati mo rin jina sako
Ogbemi wa si le lapa re
Nibiti papa tutu wa
Chrs:Emi yo ninu re.
3. Ire atanu re yi mi ka
Oreofe re n san bi odo
Emi re nsonosi nse tunu mi
On bami lo si bikibi
Chrs:Emi yo ninu re
4. Emi yo da bire nijo kan
Oso eru wuwo mi kale
Titi di gba na hun o so olooto
Nsise ofa dele re
Chrs:Emi yo ninu re.
5.