Loading...

Download
  • Genre:Afrobeat
  • Year of Release:2008

This song is not currently available in your region.

Try the alternative versions below.

Lyrics

Wa damilola o, koma je nmonira, wa funmilayo, k'aye mi dun bi oyin

Fumi lokan bale k'aye ope tun le mayo


Wa damilola o, koma je nmonira, wa funmilayo, k'aye mi dun bi oyin

Fimi lokan bale k'aye ope tun le mayo


Ninu oyun ki atowa, eda nje eda nmu, a de'le aye tan, nise bere lógán


Tori esin ma lolohun allah, ni atori e w'aye

Lofi jewipe, pelu abe ifari

Won a fa'run a dan, kato wa gba suna


L'ojojumo t'aba ti nwe, won a lowa l'apa

Won a muwa l'ese, won a fikan ibadi


Ese debi ojugun, iyen a pade pel'ori

Iqamah tafin nkirun, won a pe siwa leti

Iyen wa fun pe kole mora t'asiko ba to


Tori t'omo ba p'omo odun meje lao ma f'irun ko

Ati sin e debi oriyin koje kinle mase o

Awe ati irun timo tin nkibo, sign si oba nla


Wa damilola o, koma je nmonira, wa funmilayo, k'aye mi dun bi oyin

Fimi lokan bale k'aye ope tun le mayo


Eni toba yan ori olola lema r'eyan sofun

Pe k'omo ologo to débuté ayo, a ri opo ogun


Bere nipa sulaimana, annabi ma loje, won ma royin nti oju e ri, koto dipe osise pe


Seti annabi ayuba tamo, pelu annabi nuhu

Eni fe d'eni nla, ko mura irin ajo, ona ta nfojusun, tio sona àbùjâ


Af'eni bama sare, eyi tolohun o ni a sa, Kato le debe, ao ririn to jin

Ki irin ajo mi ma bami leru, Allahu bansho


Wa damilola o, koma je nmonira, wa funmilayo, k'aye mi dun bi oyin

Fimi lokan bale k'aye ope tun le mayo


Òpè oyinbo fi didun s'ewa ègûn tope wa nko

Òpè oyinbo fi didun s'ewa ègûn tope wa nko

Sebeyan nio n'ifokanbale pelu owo e toni


Bi aisan loba nfa keniyan o la koma gbadun ola

Haa!

Eyikeyi toje o allah, kobawa satunse, k

Keda o lola n'ifokanbale, kilowa dun to nao?


Ese loba nfa idina Ayo, allah sanu won

Fiwon lokan bale k'aye ope tunle ma yo


Wa damilola o, koma je nmonira, wa funmilayo, k'aye mi dun bi oyin

Fimi lokan bale k'aye ope tun le mayo


Boseje ile aye nbi lawa, tatin nra alijanna

Kawa ile aye tan o, lai rayo figbe


Oshi ose sunna, koma lo di ikanra

Tori ìsè leje k'omoluwabi o mase ìpátá


Wa funwa lowo allah, owo yen sekoko, Kii kuku se po ntan allahu, sebi todo re ni?


Eda tio ni wa fun lesi ayo, ko gba letter oore

Awon ton njadun konma je ikoro, koma fi s'opin oore


Wa damilola o, koma je nmonira, wa funmilayo, k'aye mi dun bi oyin

Fimi lokan bale k'aye ope tun le mayo


Mashaallah


Inu didun lo nmori ya

Lo nmori ya

Asiwaju o gbodo toshi

Eni a pelori o gbodo d'iru, ma f'owo gbeyin je a rowo na


Eni toni phone ton browse, tora data sorie

Ti data e ba tan peren, lasan, tio sowo tio fi renew


Handset a wa jobi agolo tio si miliki ninu e

Tonba l'awe kilode to browse

Ani ooooh

Se o mope inu didun lo nmoriya?


Lo nmori ya

Asiwaju o gbodo toshi

Eni a pelori o gbodo d'iru, ma f'owo gbeyin je a rowo na


Sebi ibise lawe nwa lojumo, ago mefa lonlo sile

Lago mejo o siwa nibise tio losile

Won bere kilode?

O funwon lesi o lonse oun bi koun mai loni, ago mejila lo dele


O pe'yawo e ko shilekun loru t'awe dele

Tori p'otimo peni tio gbowo nepa lowo e

Yio ti sun koto de, koto tundi peni naa a ji

Awee


Oun a tunti sa kuro nile, olohun wa ba nsowo fun

Torinu didun lo nmori ya


Lo nmori ya

Asiwaju o gbodo toshi

Eni a pelori o gbodo d'iru, ma f'owo gbeyin je a rowo na


Haa!

Seb'eni kan lo jenikan lowo, 5000 lowo toya, ou kini, osu keji koi san


Haa!

Leni toje lowo bawa npariwo, owo to jemi loni ni wallahi,

Tinba gbowo mi kin kan


Won wa bere lowo eni to yawo kilode tio san?

O lowo t'oun ya, oun fi sanwo toun tun jenikan ni


3500 loun ya, sewa ri 1500 toku

Loun dogbon si t'awon fi jeun pelomo ataya

O l'oja tio ya, loun fi ya'wo sanwo toun ya


Ogun a nya owo sanwo taje, olohun ka kuro nile

Ttorinu didun lo nmoriya


Lo nmori ya

Asiwaju o gbodo toshi

Eni a pelori o gbodo d'iru, ma f'owo gbeyin je a rowo na


Mashaallah!

Yah robbi oba nla to leto f'eni ba maa ke

Owuro mi eko

Osan mi igbiyanju

Kotodi irole je kin nko ola jo ilahi oba nla


Olohun

Ma pami ti ninu anu re


Ha!

K'eyin ma digba Toba nka tan, kooto ni kinwa j'eran

Maje kodigba togbo ba detan, kijo ayo toto sinlese o


Olohun

Je nma fela loju osan mi titi dale kin nma je igbadun

Kon bimi lowo kinma ri funwon


Kon lawon fe ile kinma ko funwon, kon bimi loko kin nni kon tokasi

Ha


Owo mi ola mi, ko wulo fun tebi tara o

Owo mi, ola mi, ko wulo kin nma nr'ore se


Alafia mi, oro mi, ko wulo fun tomo taya

Owo mi, ola mi, ko wulo kin nma nr'ore se

Irori mi, ebun mi ko wulo f'awon fans mi


Owo mi, ola mi, ko wulo kin nma nr'ore se

Ike mi, igbiyanju mi, ko dayo fawon omo egbe mi


Owo mi, ola mi, ko wulo kin nma nr'ore se

Ooooooooh!


Giga mi, ilosiwaju mi lo darun feni to nbinu

Owo mi, ola mi, ko wulo kin nma nr'ore se


MashaaAllah!

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status