Iya Alariya Lyrics
- Genre:Holiday
- Year of Release:2019
Lyrics
Iya Alariya - 9ice
...
Eminikan ko mo wa moni baba nigbejo
Mowa owolo mopade ola ati iyi
Iyalariya keke ee. ×2
Iyalariya keke majo mayo
Iyalariya keke ee
Timobalo pelu imo kan
Tabi morekojalo pelu inu kan
Shadede ni blessing awa sodomi tori mo gbagbo.
Egbegberun shubu lotun losimi
Nkankan kole she omo olorun,ojawopo ni temi
Eminikan ko mowa moni baba nigbejo ×2
Mowa owolo mopade ola ati iyi lona
Iyalariya keke ee ×2
Iyalariya keke majo mayo
Iyalariya keke ee
Ise owo mi konidibaje,Biwon tie dun wurumowurumowurumomi ,won ko fete
Baba ti sheleri pe majayemi pepepepe
Atepe lese ntemo
Ajoke aye Asake orun,koleshimi lona
Eye shenu bibi simi mo, moni baba nigbejoo.
Eminikan komowa moni baba nigbejo
Mowa owo lo mopade ola ati iyi lona
Iyalariya keke ee ×2
Iyalariya keke majo mayo
Iyalariya keke ee
.........