Pete Pete ft. ft. Asa Lyrics
- Genre:Holiday
- Year of Release:2019
Lyrics
Pete Pete ft. ft. Asa - 9ice
...
ojo re bi ana t'agba ominira
1960 nigbayen it is easy
gege bi won se wi
t'arugbo t'omidan lo n dunnu pe a ti gba ominira
omi-inira indeed abi e wo naira wa
ilu polukulumusu ewe t'agba
lo n je iyan won ni isu
a bi e o ri, ewe e ri sugbon e o fe wi
a bi e o ri, agba e ri atenuje lo fe pa nyin
Pete Pete ta na ni opa
eni ba taa ba ko maa fe ni
shey ibe le ma sun (te ba so pe e o mo nkankan)
eyin aro le ma wa (mewa n sele)
shey ibe le ma sun (eni n wo iseju akan o)
eyin aro le ma wa (mewa n sele)
kini suuru ti o lere
kini ise ti ko si ere
gbese leyan to l'oruko
o kuku sise o de ri ere
Ah e de sope a si wa l'omode
nkan sha l'eye n je ki agbado to de
9ice oro gidi lo so oro to ni laari lo so
a'ni la ti fi laakaye ka soro sibi t'oro wa
shey ibe le ma sun (te ba so pe e o mo nkankan)
eyin aro le ma wa (mewa n sele)
shey ibe le ma sun (eni n wo iseju akan o)
eyin aro le ma wa (mewa n sele)
o di asiko Ibo yen, won wa s'adugbo
won a s'omo jeje
e je k'won wole tan gbogbo eje ton je la wo lo kese
to ba tun se were lasiko Ibo
won ki odo to lo bere won a senu mere kalokalo gbe nkan mi senu wuye
aditu to wole ta lo dino fun
pasan ta fi na iyale o n be lori aja fun
odo e lo tun ramu
e ma jeun gbagbo ni funfun
fun yin, mo wi temi
asegbe kan ko si o
asepamo lo wa, ase sile la bo wa ba
emi o ti i ku mo si le sise
mo si le f'owo we owo mo si le tun le mi se
shey ibe le ma sun (te ba so pe e o mo nkankan)
eyin aro le ma wa (mewa n sele)
shey ibe le ma sun (eni n wo iseju akan o)
eyin aro le ma wa (mewa n sele)
oh oh oh oh le ma sun(Asa omo nla)
yeah yeah yeah (le ma sun)