Loading...

Download
  • Genre:World Music/Folklore
  • Year of Release:2017

Lyrics

Ilu Epe/Ligali Mukaiba - Saoti Arewa

...

Bisimillahi rahmoni roheemi

Loruko olohun oga ogo

Omo egbe arewa eje ka'sere o

Loruko olohun oga ogo

Oba ti o bimo teni kan obi o

Loruko olohun oga ogo

Olohun ti o l'orogun ti o l'obakan

Loruko olohun oga ogo

Laila illa allahu

Loruko olohun oga ogo

Egbe arewa ejeka'sere o

Loruko olohun oga ogo

E waso funmi, ona wo ni saoti ogb'orin gba

Bo tile je pe orin esin ni

E waso funmi, ona wo ni saoti ogb'orin gba

Bo tile je pe orin esin ni

Eje orin ni, baba mi Hakibu Salami o

Fi na se saoti baba Habiba

Ohun orin ni, sho'gbohun lii lola ari o

Mama mi ramota mi Agbeke

Mo ko se yanju lodo Isiaka Salami o

Gbogbo ee lo pe sowo Abefe

Ogbon maa dun, ola to n bi won ninu

Epe ni won bimi l'Eyinbi ni won wo mi dagba, Epe n'iya mi l'oke oba nile ajanasi o, dele onigba loke bosun o

Ijebu-Epe ni baba mi ajiroba, original Epe toni okun la n wi, okun magbon se gun

Epe ni won bimi l'Eyinbi ni won wo mi dagba, Epe n'iya mi l'oke oba nile ajanasi o, dele onigba loke bosun o

Natural resources awa la l'eja, ilu kan so t'aiye nki Qurani mo o, Epe oni Qurani ni mi esin lo n ro n'le wa

Epe ni won bimi l'Eyinbi ni won wo mi dagba, Epe n'iya mi l'oke oba nile ajanasi o, dele onigba loke bosun o

Ilu afinju oba Animashaun Kamoru ni Ishola Kabiyesi oloja tol'Epe o, ilu olu Epe ba n gbo pa eshin lokun o, oba Adewale Shefiu ni mo nki o k'ade o pe Lori

Epe ni won bimi l'Eyinbi ni won wo mi dagba, Epe n'iya mi l'oke oba nile ajanasi o, dele onigba loke bosun o

Ilu alfa ni eleshin n popo, sheu Musinu ali Mogasin eedu, sheu Abdul Lateefu mi, Alhaji Amuni ti o si mo, sheu Idirisu ati Ibikunle Akando, sheu Gayanbiu at'ajanasi n'ile oni mongi, imamu n'Ijebu, imamu l'Eko Epe totiku bawa ke won

Epe ni won bimi l'Eyinbi ni won wo mi dagba, Epe n'iya mi l'oke oba nile ajanasi o, dele onigba loke bosun o

Agba l'Epe o ninu oselu l'aiye eedu Sarumi, Otedola Epe ni ilu agbanla jobi, seriki baamu Lanre Rasaqi mi Adeyemi ikuforiji nko, ilu gomina eyi toni ilu eko oko Bolanle, ero ke e ma bami ki Ibidapo mi Akinwunmi Ambode o

Epe ni won bimi l'Eyinbi ni won wo mi dagba, Epe n'iya mi l'oke oba nile ajanasi o, dele onigba loke bosun o

Ilu erin nla to nfohun la ja ona beni, Ligali Mukaiba mi Alade, ilu moo ka ninu olorin ma ni Ligali baba Risika

To ba wa j'orin, ni t'olorin

To ba wa j'orin walahi o mawa o, l'Epe oloro kas'otito iwaju ni won gbe

To ba wa j'orin, ni t'olorin

To ba wa j'orin walahi o mawa o, l'Epe oloro kas'otito iwaju ni won gbe

Ninu olorin oga agba ni Ligali

Ko s'olorin ti o fowo pa'da ee loju

Apade alude orin ye baba Shamusin o

Alade totun jora e loju

Mo l'agba olorin, ati jijo morawa

E sofun omode koma ta felefele, oye kelegbe megbe

Omi olokun

Omi olokun, omi olokun kii s'egbe osa o, e sofun omode kogbon

Omi olokun

Omi olokun, omi olokun kii s'egbe osa o, e sofun omode kogbon

Ol'olorin wewe teba ri ibi t'Alade joko si

Keni keni ma ta felefele, ta ba r'eni tota felefele efele a gbe won ni i gbe yeye o, t'erin ba n lo s'ode re o egberun aja o loode k'ederin duro

S'ode e o, egberun aja o loode k'ederin duro

Lunu Alade o, agba orin wa lenu Alade o baba Risika Alade o, agba orin wa lenu Alade boje begbebu

Alade o, agba orin wa lenu Alade o baba Risika Alade o, agba orin wa lenu Alade boje begbebu

Asia te gbe ninu orin tiwon ko ilu Epe si

Ohun ni Shamusideeni ngbe

Ounbe lowo Akeemu Adewale

Ati Adeniyi Saheedi mi Ligali

Owa lowo ee, lowo ee

Owa lowo ee Titilope Alade Issa Ligali

Owa lowo ee, lowo ee

Owa lowo ee Titilope Alade Issa Ligali

A jo magbe ni olorin tobati bi s'Epe o

Tunde Ayinde baba Diana

A jo magbe ni olorin tobati bi s'Epe o

Tunde Ayinde baba Diana

Saoti olorin, olorin

Saoti olorin, ounbe lowo mi laye koni jabo

Saoti olorin, olorin

Saoti olorin, ounbe lowo mi laye koni jabo

Shey ka s'otito, itan nle itan nbi

F'eni toba loye ti n shey pelepon to soro, ko le si lowo mi abuku omo Mukaiba, eniwi loju mi, mi o ni dele ki nto fesi o Ligali i s'eni ariifin o

O ye ko wuwo lenu yin ki lese so, pe'rumi lenu ti o fi bu Ligali, emi kii se iru yin

F'eni toba loye ti n shey pelepon to soro, ko le si lowo mi abuku omo Mukaiba, eniwi loju mi, mi o ni dele ki nto fesi o Ligali i s'eni ariifin o

Itan timo pa awon mejeji to l'oro o si mo, won wi ni won e so, tebawa sope o ku di e kaa to o di t'eni sofunmi

F'eni toba loye ti n shey pelepon to soro, ko le si lowo mi abuku omo Mukaiba, eniwi loju mi, mi o ni dele ki nto fesi o Ligali i s'eni ariifin o

Kinni hun o fi so o ye k'enu na o faya ni, eku agboye gbogbo omo Ligali t'iyawo t'ebi pelu ololufe wa, eku i f'omoniyan se

F'eni toba loye ti n shey pelepon to soro, ko le si lowo mi abuku omo Mukaiba, eniwi loju mi, mi o ni dele ki nto fesi o Ligali i s'eni ariifin o

Bi ibi o ba wo beyin o ba te looto, egbe baba eni oto s'oko iya wa, Ligali baba Risika

Omo asa ni, omo asa ni

Eni bu egbe daddy ee omo asa ni

Alade mi o, je bawon bu ee

Ligali mu, Mukaiba Mukaiba baba wa ni

Ore baba mi Hakibu Salami lehindini, akewu gberu forun ke ajiroba

Omo asa ni, omo asa ni

Eni bu egbe daddy ee omo asa ni

Alade mi o je bawon bu

Similar Songs

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status