Pregnancy Palava 5 ft. Kelly J vibez & Mcdesktop Lyrics
- Genre:Spoken Word
- Year of Release:2022
Lyrics
Pregnancy Palava ft. Kelly J & MC Desktop - Finestz
...
Haaaa!!!
Daddy mi
Daddy mi
Daddy mi
E se? Iru pipe wo ni yin
Se mo daku ni
Baba mi kin lol sele
Oyun ti po'su mejila
Se ko ye kin tin bimo ooo
Woju mi omo mi
O ma ni loyun a ni rorun
Emi gan ti jade si
A Fi ka re ni to loyun
Won de ooo
Se iwe le mi le mu wa ni
E wo bi won se wo bi aji eran gbe
Baba jungunu omo jebete
lo ni te wa yii, e ma lo setel
Ode alakori se mo joor eni to fe wa le yin
Oponu alaboyun se gan joor eni to reti yin
woju mi omo mi, ma dohun lohun o
Oyun to ni o sha ye ko ti bi mo o
Talo omo yin? Baba egbe mo iye omo to bi
Haaa!!! omo egbe ma se binu si baba egbe
Se mo joor doctor ni
Kilo kan mi kan oyun omo ale
Koro gba lenu re
Se emi mo loyun omo ale
Alfa pe e
Te le wa ka lo ooo
Alfa ko onifa ni
Wa lo ni
Mio lo
Bo se gbigbe
Mio lo
Bo se lilu ooo
Mio lo
Wa lo ni
Mio lo
Haaa! Haaa!!
Baba ruka
Haaa!!!