Gbemidebe ft. Qdot Lyrics
- Genre:World Music/Folklore
- Year of Release:2022
This song is not currently available in your region.
Lyrics
OP Dot! gbewalo ooo (2t upon the beats)
Omomomoriamo ooo (DJ OP DOT I love you)
Ungba Ungba Ungba Alagbe Ungba Ungba Ungba
Qdot loruko mi timba ni gbetiti gbegbe ungbe ungbe
Ki l'onje ta jeri "Gbemidebe"
Packaging lo pa Lekki "Gbemidebe"
Won ni o se kan to seri "Gbemidebe"
Kosi barber ti o le geri "Gbemidebe"
Haircut lo ma yato "Gbemidebe"
Happy hour lori Molly "Gbemidebe"
Idunnu lo subu layo "Gbemidebe"
Alagbe le salaye "Gbemidebe"
O ngbe mi trabaye "Gbemidebe"
Irole lo ma nwe "Gbemidebe"
Awon omo mi loruloru "Gbemidebe"
Kafaya Gbemidebe
Karimo Gbemidebe
Jenifer Gbemidebe
Ori mi lo fe fa "Gbemidebe"
Alhaja Memuna "Gbemidebe"
Eleha to nse stripper "Gbemidebe"
Awa o ki nawo fun egun "Gbemidebe"
Be se ndaso boju "Gbemidebe"
Akori koda Gbemidebe
Buju ti p'oruko da Gbemidebe
Odori odori Gbemidebe
Alhaja lohun o bori Gbemidebe
Ogbowo ko fe sori "Gbemidebe"
Mo mo po momi "Gbemidebe"
Lo se nfobo lo mi "Gbemidebe"
Lo bere mi n'ilu Ibadan "Gbemidebe"
Won ma je ko m'otan "Gbemidebe"
Igboro mo mi "Gbemidebe"
Igboho oosa gan mo mi "Gbemidebe"
Omo anibon majale "Gbemidebe"
Omo ajale ma gbowo "Gbemidebe"
Ororun mi ni "Gbemidebe"
O ri pampa "Gbemidebe"
Idi nla gbamgba "Gbemidebe"
Ko n'ise lapa "Gbemidebe"
Eni tan bo to nbo aja "Gbemidebe"
Ti picker ba gbowo lo "Gbemidebe"
Middle man lo je gbese "Gbemidebe"
B'ebi ba pa were "Gbemidebe"
Were ma ja w'oja "Gbemidebe"
Egun ara orun "Gbemidebe"
Ohun gan hustle laye "Gbemidebe"
Trust nobody Gbemidebe
Olamide Gbemidebe
Ko m'onu Enimony "Gbemidebe"
Ninu aye Gbemidebe
Won njoju anybody "Gbemidebe"
IBD Dende Gbemidebe
Alaye ma ngbemidebe "Gbemidebe"
MC Oluomo Gbemidebe!
L'ekole omojuomo "Gbemidebe"
Arowolo lo nta motor "Gbemidebe"
N'ilu Atlanta "Gbemidebe"
Eba nki Mama Kay o "Gbemidebe"
Mummy OP Dot! "Gbemidebe"
Eyan Qdot Gbemidebe
Mayegun gbogbo Dubai "Gbemidebe"
Ijebu o fowo sere "Gbemidebe"
Won f'ise sere "Gbemidebe"
Mo mo Tunde Adigun "Gbemidebe"
Adigun abule sowo "Gbemidebe"
Kogbagiidi Gbemidebe
Billique 60 - 40 "Gbemidebe"
Bukunmi Mama Meto "Gbemidebe"
Climax lo nse visa "Gbemidebe"
Dakun ma se transfer "Gbemidebe"
Kaala Gbemidebe
Ranju Gbemidebe
Akala gbogbo Golo "Gbemidebe"
Momo alase gbogbo Turkey "Gbemidebe"
Otunba cash "Gbemidebe"
Mo mo Sanwo Ayanlu "Gbemidebe"
Akinrogun owo mi da "Gbemidebe"
Mo ni mo moja omode "Gbemidebe"
Eyan Okoko Gbemidebe
Okoko dakun ma yinbon "Gbemidebe"
Kunle poly Gbemidebe
Eyan Barryshine "Gbemidebe"
Gbemidebe "Gbemidebe"
Oni motor gb'emi sare "Gbemidebe"
OP DOT Gbemidebe
2t Gbemidebe
2t on the mix