Ogo (Remix) ft. 9ice Lyrics
- Genre:World Music/Folklore
- Year of Release:2022
Lyrics
Ogo (Remix) ft. 9ice - Koller
...
ogo to n sha'nan
monan-monan a tan'nan imole
omo ologo a koja o,
oogo mi aa tayo
ogo to n sha'nan,
ki'rawo mi tan-nan
kori mi bamise o,
je ki n ri batise
olorun mi,
ogo to n sha'nan
to n sha'nan, to n gbope, to n, to n
to n ra motor, to n jaye, to n kole,
to n fo loke, to n jaye oba,
ta n so n'igboro
tori pe mo nice,
omoba, won ti funmi ni breakfast twice
after to freestyle, nothing to entice
just because say emi ati sapa a unite
then i called Jehovah
oba to ni gbogbo nkan lowo
p'agbara bi ara nbe,
dahun soro mi o,
temi o nii soro se lodo re baba~
ogo to sha'nan,
ogo to n sha'nan
monan-monan a tan'nan imole
omo ologo a koja o,
oogo mi aa tayo
ogo to n sha'nan,
ki'rawo mi tan-nan
kori mi bamise o,
je ki n ri batise
olorun mi,
ogo to n sha'nan
to n sha'nan, to n gbope, to n, to n
to n ra motor, to n jaye, to n kole,
to n fo loke, to n jaye oba,
ta n so n'igboro
Aa'lore soro, pe ma s'ori ire
Mo gbagbo,
Emi mo banu arami soro, pe ma sori ire
Mo te'pa mo'se owo mi
Awon tan dagunla n bawa yo
Olorun mi nbo, you'd better wait
Ile ayo, a kowa po
ogo to n sha'nan
monan-monan a tan'nan imole
omo ologo a koja o,
oogo mi aa tayo
ogo to n sha'nan,
ki'rawo mi tan-nan
kori mi bamise o,
je ki n ri batise
olorun mi,
ogo to n sha'nan
to n sha'nan, to n gbope, to n, to n
to n ra motor, to n jaye, to n kole,
to n fo loke, to n jaye oba,
ta n so n'igboro
Ogo to n tan-na,
Ogo ti o Ju
Irawo mi tii tan-naaaa