O Gbogbo F'olemi Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2021
Lyrics
O Gbogbo F'olemi - Apekeola
...
oba to sokun mi derin
oba to soegan mi dogo
ewa womi emi gangan leri oh oh oh
nibi tayemi ti nilo iranlowo
ofogo waye miri
o wa so ofo dogo
ode pada wa gbogo Fole mi
anu tenikeni Ori gba ninu Iran mi ri
anu to so esteri erulasan dayaba lafin oba oh
anu to so obedi odomu olori buruku do lorire
emi ti mi o ni reti ola
owa somi deniyan Pataki
ole alailagbara je ni ti o nireti ogo
enitola o tosi ti o ye fogo
owa so di eni to gbo gbo aye celebrate olorun iwo ni
eni to n woju omo eniyan lati mo so losenu to wa deni to n funi lounje
oku ku to mi ole olorun
koto gbogo Fole mi
ani o gbogo folemi
o gbogo folemi
emi alaileniyan rara o de pada wa gbogo folemi
o le ni mi alailagbara oh
o ku ku rimi lole koto gbogo folemi
oya sowipe
ogbogo folemi
ogbogo folemi
emi alaileniyan rara rara o de pada wa gbogo folemi
gbogo folemi
gbogo folemi
emi alaileniyan rara rara o de pada wa gbogo folemi
eninla olodu to mare Toto
eninla olodu to mare ibare oh
wiwo lule bi ase ileke
arabaribiti aribirabata alejo to n seonile lokonrin kese
oke rabata
oke kenke
oke fen fen
oke gbangba
arugbo lai Lai
arugbo igbani
emiinu awon woli to to
odada aye
odada orun
odada ojo
odada ile
eni keta ninu ina