Loading...

Download
  • Genre:Spirituals
  • Year of Release:2021

Lyrics

Oriki olorun - Mr Jemsoul

...

chorus:

Iba lawa koko se f'oluda aye

Iba lawa koko se f'olorun orun

Kabiyesi baba wa ti o je a tawo na


Iba lawa koko se f'oluda aye

Iba lawa koko se f'olorun orun

Kabiyesi baba wa ti o je a tawo na


verse 1:

N o ki bi ologun eru ooooo!

N o ki bi elegberun iwofa!

Oba nla , olorun nla

Alade nla, O n gbebi nla

Olorun Ajobo, eru jeje baba awon eru.

Olodumare noooo!

Oba atayero bi agogo

Oba to tele bi eni teni.

Olukangun orun, ajosin odumare.

Oro pa, oro ji, oro gbenu orun sogo

Alagbara nla ti o se fija lo.

Emi o le ki o tan o, baba mi.

Eyi ni mo se m'eni keji mi wa,

Nitori tako tabo le dawa.

Oba to n sise re tiyanu tiyanu,

Olorun ara, olorun iyanu.

Awamaridi to gbogbo aye npe ni YAHWEH!!!!!!!!!


chorus:

E je ka jo yin'lorun oo!

E je ka yin'ledumare.

Apa nla, to saye ro,

E je ka jo gbega o.

(Kilewi)

E je ka jo yin'lorun oo!

(Yeeba)

E je ka yin'ledumare.

(Ahan)

Apa nla,

(yeee)

to saye ro,

(Aahhh)

E je ka jo gbega o.


verse 2:

Oponu eniyan woye titi, o ni lo s'olorun.

Akindanidani wo titi o ni ko si wahidu.

Nibi tomo kootu ojirebi ti nse kaa-bi-ye-si

Tomo Nna ti nkan Sara soba mi to ni "Odgwu"

Gambari, Fulani ati Hausa paapa mo riri baba mi

Won nse "Yan-ka-de-de"

Oba to ti nbe kaye to maa be,

Oba to ti wa kaye to wa.

O gbeni nija Keru o bonija,

Baba mi o ranmo nise fayati, olorun awon omo ogun.

Your Excellency sir, His Royal Highness.

Oba to to gbadobale gbogbo oba patapata porogodo.

Patapata ola, porogodo yin.

Ajulo to n fajulo han ni gbogbo ile kile.

O f'ajulo han titi, o tori alaseju bomi gbigbona.

Baba mi akomatika leyin.

Jehovah Shalom, babanlaku baba mi atori eni ti o sunwon se.

Bi mo ba ni kin ma ki o, ile a su, ile a mo.

Egbegberun iran a koja lo.

Bi mo tile legberun ahon, gbogbo re o to lati yin oba mi oke.

Oluda aye, aseda orun, oba nla ti o se gbenija.

Eyin ni Jehovah Elohim

(Olorun Ayeraye)

Jehovah Shalom

(Oluwa ni alaafia wa)

Jehovah Elohay

(Oluwa wa)

Jehovah Shammah

(Oluwa nbe nibi)

Jehovah Jireh

(Oluwa ni olupese wa)

El Saboath

( Olorun awon omo ogun)

Onise iyanu ti gbogbo aye npe ni YAHWEH!!!!!!!!!!

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status