Alaa Mi Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2021
Lyrics
Alaa Mi - Esther Opalemo Adegboyega
...
Alaa mi gba agbara lati wa si imuse o
Iran rere mi gba agbara lati wa si imuse o
Ojo ola mi gba agbara lati wa si imuse o
Oun rere gbogbo ti Oluwa ran mi wa se ninu aiye gba agbara lati wa si imuse o
Jade kuro lewon bere sini fohun ninu ogo
Alaa ibi giga ti mo ni gba agbara lati wa si imuse o
Iran pe ma d'orilede nla gba agbara lati wa si imuse o
Asotele rere ti ati so sinu aiye mi gba agbara lati wa si imuse o
Awon oro rere tati so nipa temi ninu iwe mimo gba agbara lati wa si imuse o
Jade kuro lewon bere si ni fohun ninu ogo