Loading...

Download
  • Genre:Afrobeats
  • Year of Release:2006

Lyrics

Recompense IV - Sulaimon Alao Adekunle Malaika

...

Ẹ tẹẹti ẹgbọọ nípa ẹyọ oo

Biwon ṣe fà pena ni jọ yẹn tí wọn ò dagbere jo

Ẹ tẹẹti ẹgbọọ, Ẹ tẹẹti ẹgbọọ nípa ẹyọ oo

Biwon ṣe fà pena ni jọ yẹn tí wọn ò dagbere jo

Ẹ tẹẹti ẹgbọọ nípa ẹyọ oooo

Biwon ṣe fà pena ni jọ yẹn tí wọn ò daagbere jo oo

Ẹ tẹẹti ẹgbọọ, Ẹ tẹẹti ẹgbọọ nípa ẹyọ oo

Biwon ṣe fà pena ni jọ yẹn tí wọn ò dagbere joo

Wọn tí dà jọ ilu rọgẹdẹ ó patijade titi dúró

Wọn tí dà jọ ilu rọgẹdẹ ó patijade titi dúró

Wọn tí dá ẹlẹya àwọn tó sanwo àga wọn leleriwo

Àwọn tó wọ mẹẹta tẹgbẹrun àwọn lílu mẹẹta tẹgbẹrun

Ẹyọ kú ìjọ mẹta soun lari bàbà àgbà ton lagogo

Ẹyọ kú ìjọ mẹta soun lari bàbà àgbà ton lagogo

O lori ẹlẹyọ ilẹ yí ẹgbọ o

O lori ẹlẹyọ ilẹ yí ẹgbọ o

Pẹlu gbogbo ẹyọ too má jáde

Pẹ̀lu gbogbo ẹyọ too má jade

Wọn sọ pé ọba liida npe wón

Wọn sọ pé ọba liida npe wón

Ìja tí kún rẹpẹtẹ, Kabiyesi ọba dede nsọ fún won

Ye! Ìja tí kún rẹpẹtẹ, Kabiyesi ọba dede nsọ fún won

O lórí dókítà lọ ràn ni soun

O lórí dókítà ohun lọ ràn ni soun

Wípé kí ẹyọ náà kò sí yẹ

Toripe kò náà kan nígbà yẹn

Lariwo bá táá, larimu bá yà rí eko tagidi fàṣaa

Lariwo bá táá, larimu bá yà rí eko tagidi fàṣaa

Ohun gbọ tọ lọ gẹdẹ ó sọ fún onípò

Ohun gbọ tọ lọ gẹdẹ ó sọ fún onípò

Wípé kí ẹyọ yìí yẹ ẹ seke

Ẹyọ náà ogbọ lọ tún yẹ mo

Kí ẹyọ yìí yẹ ẹ seke

Ẹyọ náà ogbọ lọ tún yẹ mo

Ilẹ̀ máa mo, larimu bá lọ kó ẹyọ rẹ bọ sí gbangba

Ilẹ̀ máa mo ooo, larimu bá lọ kó ẹyọ rẹ bọ sí gbangba

Ẹyọ tó kú lẹ́yìn, wọn ba safi ya wọn

Gbogbo ẹyọ tó kú lẹ́yìn wọn ba sa fi ya wọn

Wọn ba nimu soku ni bí òkú

Àná relu gọọtá lọ nàwọn

Ẹyọ lọ boodo ẹran ọ̀pá àná relu gọọtá lọ nàwọn

Ama ṣá, ká lagodo mú agodo rẹ daani àṣẹ yọ tán àṣẹgun rikiiṣi asimaa jọ pá ẹ bóyá o asimaa jọ pá ẹ bóyá ooo

jọ pá ẹ bóyá ooo, asimaa jọ pá ẹ bóyá ooo

asimaa jọ pá ẹ bóyá ó, asimaa jọ pá ẹ bóyá ooo


"uunn" eko àkéte ooo, ọba jẹ orojuu, eeko àkéte ooo, ọbọ jẹ orojuu, kí Olúwa Ọba ó, jẹ ko tútù mini mini, àwọn ìṣe ń ṣe aru rè óò, eeee!

Ẹẹ! Ìyá mi má numi kí oto rami nù tó bá numi má gbé ẹ jẹ ooo

eeko àkéte ooo, ọbọ jẹ orojuu, koooo Olúwa Ọba ó, jẹ ko tútù mini mini, àwọn ìṣe ń ṣe aru rè óò, eeee!

Ọ̀pọ̀ oyinbo fi dundun rẹwa, ẹgun wa lára rẹ, olele riwo wo wo

eko àkéte ooo, ọba jẹ orojuu, ki Olúwa Ọba ó, jẹ ko tútù mini mini, àwọn ìṣe ń ṣe aru rè óò, eeee!

Congratulations ẹkùn bàbà Kolawole, olowo eko bàbà Barrister lawyer tó njẹ

Similar Songs

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status