Loading...

Download
  • Genre:Gospel
  • Year of Release:2019

Lyrics

Covenant God (Olorun Majemu) - Tejumola Oyebowale

...

Ọ̀lọ̀rùn ní ọ́

Pẹ̀lú Májẹmú

O tóbi o

Jayé ọ̀run lọ.

Ọ̀lọ̀rùn ní ọ́

Pẹ̀lú Májẹmú

O tóbi o

Jayé ọ̀run lọ.

....

O dá ayé

Ó fi sọlẹ̀ sorí omi

O dá mi l'énìyàn

O ò dá mi l'ẹ́ranko

Ẹyẹ ojú ọ̀run iṣẹ́ ọwọ́ rẹ ni

O tún dá afẹ́fẹ́ pẹl'áwọn òké ńlá

Àwámárìídìí ni iṣẹ́ ẹ̀ rẹ èdùmàrè.

Ọ̀lọ̀rùn ní ọ́

Pẹ̀lú Májẹmú

O tóbi o

Jayé ọ̀run lọ.

Ọ̀lọ̀rùn ní ọ́

Pẹ̀lú Májẹmú

O tóbi o

Jayé ọ̀run lọ.

Ó bá Sárà dá májẹ̀mú nígbà tiódogbó tán

Ó ní ní'wò yí àmọ́dún wàá gbọ́mọ ọkùnrin jó

Ẹgbọ́ báwo lóṣẹ fẹ́ jẹ́ kárúgbó lóyún kó sì bímọ

Kábiọ́òsí Ọba to sọ arúgbó dọlọ́mọ

Ọlọ́run o Ó dára ò ó tóbi.

Ọ̀lọ̀rùn ní ọ́

Pẹ̀lú Májẹmú

O tóbi o

Jayé ọ̀run lọ.

Ọ̀lọ̀rùn ní ọ́

Pẹ̀lú Májẹmú

O tóbi o

Jayé ọ̀run lọ.

Ará ẹ̀wá bá mi jó,

Ọ́rọ̀ mí dayọ̀,

Mo f'ògo f'ólúwa.

Ará ẹ̀wá bá mi dúpẹ́,

Ọ́rọ̀ mí dayọ̀,

Mo f'ògo fún baba.

Ọ̀lọ̀rùn ní ọ́

Pẹ̀lú Májẹmú

O tóbi o

Jayé ọ̀run lọ.

Ọ̀lọ̀rùn ní ọ́

Pẹ̀lú Májẹmú

O tóbi o

Jayé ọ̀run lọ.

Gbé óluwá ga pẹ́lu mí ẹyín éniyàn rẹ,

Kì gbogbo ẹ̀dá alààyè máa yọ̀ lòorúkọ rẹ̀ ,

Fún ìfẹ̀ tí ó fi hàn, Fún ísínmí lọ́kàn wa,

Fún ígbalá kíkún rẹ̀, Tirẹ́ lọpẹ̀.

(Ki gbogbo wa) Ki gbogbo wa fọ'pe fún

Ki gbogbo wa fọ'pe fún

Ki gbogbo wa yìn òrukọ́ olúwa wa tití lae lae.(2×)

Ọlọ́run ni òhun ni ò

Ọlọ́run ni òhun ni ò

Ọlọ́run ni òhun ni ò

Ọlọ́run ni òhun ni ò

Ó sọ ọ̀kun di ìyàngbé ilẹ̀

Ọlọ́run ni òhun ni ò

????????????

Ọlọ́run ni òhun ni ò

Ọ̀rọ̀ ńlá tó sọ̀rọ̀ ségugun gbígbẹ

Ọlọ́run ni òhun ni ò

Ọlọ́run Agboọlá

Ọlọ́run ni òhun ni ò

You are the miracle worker

Ọlọ́run ni òhun ni ò

Ọlọ́run ni òhun ni ò

Ọlọ́run ni òhun ni ò

Similar Songs

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status