Ija dopin Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2021
Lyrics
Ija dopin - C&S Youth Europe
...
1. Ija dopin oguun si tan
Olugbala jagun molu
Orin ayo la o ma ko
ALLELUIA!
2. Gbogbo ipa n’iku ti lo
Sugbon Kristi f’ogun re
Aye! E ho iho ayo
ALLELUIA!
3. Ojo meta na ti koja
O jinde kuro ninu oku
E f’ogo fun Oluwa wa
ALLELUIA!
4. O d’ewon orun apadi
O silekun orun sile
E korin yin segun re
ALLELUIA!
5. Jesu, nipa iya t’oje
Gba wa lowo oro iku
K’a le ye, ka si ma yin o
ALLELUIA! AMIN.