Wazo Lyrics
- Genre:Hip Hop & Rap
- Year of Release:2021
Lyrics
Rasta
Mo pade iye e lana, o bili mi leni
Towo ti ku wazo, owo ti ku wazooooo
Owo ti ku wazo, owo ti ku wazo
Owo ti ku wazo, owo ti ku wazooooo
Owo ti ku wazo
Rice wazo, ewa wazo
Eran Wazo, eyin wazo
Change wazo
Oku wazo, oku wazo ooooo
Oku wazo
Awon omo Billing Billing
Awon Omo para para
Won le mi won ba mi
Mo ya japa fun won
Towo ti ku wazo, loba ni mo lahoun
Loba ni mo stingy, ma fun iya e ni twenty
Emi awa ni Thirty
Olohun mi o lahoun, olohun mi o lahoun
Olohun mi ahoun, yoruba ni wa
Housa ni zo, igbo ni Bia
Kilode Ta wa n ja, towo ti ku wazo
Owo ti ku wazooooo, owo ti ku wazo
Mo pade iye e lana (Mo pade iye e lana)
O bili mi leni, towo ti ku wazo
Owo ti ku wazoo, owo ti ku wazo
Owo ti ku wazo, owo ti ku wazo
Owo ti ku wazoo, owo ti ku wazo
Rice wazo, ewa wazo
Eran Wazo, eyin wazo
Change wazo
O ku wazo, oku wazooooo
O ku wazo, ti mo ti gbe colo
Ti mo ti la molly, ti mo ti horny
Ishan ti di thirty, penalty ni ki n goal
Na ba tun ni mo faul, werey ni refre to so be
Wazo lowo Ku, kin n Kole Kin ra Benzo
O da Bi ma shey Yahoo, kin ti e gba wire
Kin sanwo Producer, ko rin Dun Nigeria
Omo jo gba naira, gbon idi e fun Jago
Set awan Naira, colos la'iye nfa
Ma lo be soja, osun oti High
Ashey Pedla, Aje On d mix