Majenjebi Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2021
Lyrics
Majenjebi - Tosin Oni
...
majenjebi Lori won
awin to da mi fun o, ma majenjebi Lori won
awon to ko so gbe mi gbogbo, majenjebi Lori won o
baba ahah,ma majenjebi Lori won
Owo to fun mi,ipe to pe mi Tori awon kan ni
mi o sheshi waye,sebi nitori Iran mi ni
iye okan Toni ki jere waale,ma je Fi iwami Le won pada o
baba oh oh oh, majenjebi Lori Iran mi
woli mi to fi solution ayemi Le lowo,
sugbo to ti mo,ba mi wa ri, ko ma lo jebi Lori mi,olore kan shosho to Yan funmi,ki irin Ajo ko Le ya,to wo re otenumo,bami Saanu fun iru won,segun aye fun won,to ba Ron won lorun,Arun mi lorun eh
baba oh oh ma ma ojenjebi Lori mi
baba ah ah majenjebi Lori won
awon to Dan mi fun o,ma majenjebi Lori won,awon to ko so igbe mi gbogbo, majenjebi Lori won o
baba ah ah majenjebi Lori won
Omo to fun mi bi ATI eyi ti mogba to
oko to fun mi Fe,Aya to fun mi gbe
aye to fun mi lati wa,ipo to fi mi si
majenjebi Lori won
awon iseda ogo to so mo irin Ajo ayemi
to kosi jurisdiction mi ki won le je Ayan lati aran mi,ma majenjebi Lori won
awon ti Oro anumi fun itunu lo kan ooo
awon ti Orin mi Fe yi lokan pada,ti iwasu mi Fe gbe lokan to,to Eri mi Fe mu duro,ta so mi Fe bo ni wowo,to rule mi Fe bo Lori,tonje mi Fe bo yo,te se mi Fe gbe sare o,to wo mi Fe fa soke o, majenjebi Lori won,
ogbon,abun to fun mi,agbara to fun mi la TI Dari Lori Ile,ipinle,orile ede labaya je le lo pelu otito,ki ma ba jenbi,
baba ahah majenjebi Lori won
awon to da mi fun o,ma majenjebi Lori won ,awon to ko so igbe mi gbogbo, majenjebi Lori won o,leyi gbogbo re o,ma majenjebi Lori arami