Loading...

Download
  • Genre:Afrobeat
  • Year of Release:2021

This song is not currently available in your region.

Lyrics

Jafafa ft. Mohbad - Chinko Ekun

...

Imole

Mohbad

Oh ba ba bà

oh shin shon gwa

Imole

Tiger

shon woah ah!

ọmọ to bá já fáfá

ohun lo máa sha pra pra

ọmọ to bá já fáfá

ohun lo máa sha pra pra

ọmọ to bá já fáfá

ohun lo máa sha pra pra

ọmọ to bá já fáfá

ohun lo máa sha pra pra

Aṣọ oju Lagbaja

wọn ti fi lọ ran pata

CV booda nuuru

wọn ti fi ta guguru

tiger kaasa

Omo to ba já fáfá

shẹ b'oun lo máa sha pra pra

ọmọ to bá bọ pátá

credit alert lo máa gbọ pampam

awa lenu ati já fáfá

é wò lion to lo n sa faja

é lọ jabo sínú shalanga

awọn alakori lọ n rojọ wà fún lágbájá

ọmọ to bá calm down lo máa gba bone straight

ẹni feyin sí wa ló máa gba Colgate

a k'ero wọnú club won tun kígbe no space

awọn iya mi loru ọ máa kín sanwo toll gate

won be e o gbọ, wọn bẹ é o gba

wọn sa é o gbọ, wọn sa e o gba

Number e o lo, O r'oja o fa

matter yen long anaconda!!

ọmọ to bá já fáfá

ohun lo máa sha pra pra

ọmọ to bá já fáfá

ohun lo máa sha pra pra

ọmọ to bá já fáfá

ohun lo máa sha pra pra

ọmọ to bá já fáfá

ohun lo máa sha pra pra

Aṣọ oju Lagbaja

wọn ti fi lọ ran pata

CV booda nuuru

wọn ti fi ta guguru

CV booda nuuru na fi ta suya fún won

Gucci pef náà fẹ rà náà fi ta lofinda fún won

shebi é lẹ mad ni a o ni gba fún won

awọn tó ní wa ishubu wa

amin ashe ko dẹ ni dáa fún won

é máa binu pe mo n shepe

hustling for payday

mo rí wọn nínu lambo she ni won dàbí òkété

ati mọ yen tey tey, Ìdí wa leyin na ege

a fun ni máa wo bẹ ma screenshot èèyàn IBD Dende

won be e o gbọ

wọn sa é o gbọ

Number e o lo, O r'oja o fa

matter yen long anaconda!!

ọmọ to bá já fáfá

ohun lo máa sha pra ọra

ọmọ to bá já fáfá

ohun lo máa sha pra pra

ọmọ to bá já fáfá

ohun lo máa sha pra pra

ọmọ to bá já fáfá

ohun lo máa sha pra pra

Aṣọ oju Lagbaja

wọn ti fi lo ran pata

CV booda nuuru

wọn ti fi ta guguru

Similar Songs

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status