Ija D'opin Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2019
This song is not currently available in your region.
Lyrics
Ija D'opin - EmmaOMG
...
Ija dopin oguun si tan
Olugbala jagun molu
Orin ayo la o ma ko
ALLELUIA!
Gbogbo ipa n'iku ti lo
Sugbon Kristi f'ogun re
Aye! E ho iho ayo
ALLELUIA!
Ojo meta na ti koja
O jinde kuro ninu oku
E f'ogo fun Oluwa wa
ALLELUIA!
O d'ewon orun apadi
O silekun orun sile
E korin yin segun re
ALLELUIA!
Jesu, nipa iya t'oje
Gba wa lowo oro iku
K'a le ye, ka si ma yin o
ALLELUIA! AMIN.