Loading...

Download
  • Genre:Gospel
  • Year of Release:2019

This song is not currently available in your region.

Lyrics

Anu Ni Mo Fe - ADUKE GOLD

...

intro (instrument )

Iwo nikan lo moju, to peju,

to funfun ju, Iwo nikan lorinu,

to rokan gbogbo eniyan,

Iwo nikan lao Le sigba fun,

ta ole binu si, ta ole da lebii,

boti wu o lonsola, to npin ogo fun gbogbo eniyan

ose Farao laya Le, Iwo lo tun ran Mose koloba,

orile ede meji nbe ninu re, aburo la maa soga egbon, Jefta Omo ale, o tun mu pada dolu omo,

tanto the ite re lojo Idajo, ojo Anu ni ko foro misi, tanto woju re lojo Idajo, ojo Anu ni ko foro misi,

bimo ba ranti gbolohun yen o, emi o Sanu fun Eni temi o Sanu fun un, emi asi soju rere mi, seni ti ma soju rere si,

ise mako o, Anu Olorun ni,

ise mako oooo, Anu Olorun ni,

Anu nimofe (Olorun oba)

Anu nimo bere (Anu nimo bere)

Anu nimofe o, (ise kekere Owo nla ni mofe)baba ise ko low

Anu nimofe (Olorun saanu mi)

Anu nimo bere, Anu nimofe o

baba ise ko lowo (interlude)

Jacobu nimo feran, Esau nimo koriran,

ta Leni to Le mu siiii,

Iwo loda aye Olorun mi, amo oo pin Dede o,

awon kan ngbe Inu Ile, awon kan ngbe Inu Igbo ta Leni tole mu siiii, awon kan nwomo, we're bi ibeji koreni gbe, taleni to lemu o gan, Samueli rele Jesse lati lo Yan oba tuntun fun Israeli, eliabu akobi lo Koko jade, tewatewa, tigigatigiga,

Samueli rope ati roba o,

baba mi je koye wipe mokoo ,

ma woju e, mawo giga e, (mokoo)

eyan nwoju, Olorun nwokan (mokoo)

a! eyan Le rewa, koma raanu gba,

sheiii! Olorun o, awon mejeje, koja

nwaju wolii sibe, (Olorun ko won)

Anu to Sonu layee won, dafidi nlo ri e

Ori ogo nbe ninu Igbo o, Ori ogo ntoju Ori agutan,

bimo ba rantiii gbolohun yen ooooo,

emi asanu fun Eni temi asanu fun,

emi asi soju rere mi seni ti maa soju rere si, ise mako oo (Anu Olorun ni),

ise mako oooo (Anu Olorun ni)

aa! Anu nimofe, Anu nimo bere

Anu nimofe oo (baba ise ko lowo)

Anu nimofee, (Anu nimofe)Anu nimo bere

Anu kiki Eni Toba ranu gba nikan, oni Kise feni to nsare ???? Anu nimofe o, baba ise ko lowo .

Olorun lohun maa gbe o ga, o so folorun pe oo Leni kankan, tanu bade boba ranu gba, ibi giga lape o kowa logo re,

Olorun ni wo fomo sile saye lo, o so folorun wipe baba moti dagba, Toba raanu gba, Oro e Ako araye logbon pe ba oku o ise o tan, Olorun sope ohun maa kole fun o, o dolorun lohun pe o lowo iso, seni to kole funkan terin ode Nile Lori ase o pelase irorun, Anu nimofe, Anu nimo bere, Anu nikan lole banise o, Tori moripe ise ko lowo, (Anu nimofe, Anu nimo bere )

Anu nimofe o, baba ise ko lowo, Anu nimofe, Anu nimo bere, Anu nimofe o baba ise ko lowo .

Similar Songs

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status