A We O Ninu Eje Odo Aguntan Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2020
This song is not currently available in your region.
Lyrics
A We O Ninu Eje Odo Aguntan - EmmaOMG
...
. O ti to Jesu lo fun 'wenumo bi?
A we O nin' eje Od'agutan?
Iwo ha gbekele ore-ofe Re?
A we O nin' eje Od'agutan?
A we O n'nu eje
Ninu eje ti nwe okan mo?
Aso re ha funfun, o si mo laulau?
A we o nin' eje Od'agutan?
O mba Olugbala rin l'ojojumo
A we o nin' eje Od'agutan?
O ha gbekele Eni t'a kan mo 'gi?
A we o nin' eje Od'agutan?
A we O n'nu eje
Ninu eje ti nwe okan mo?
Aso re ha funfun, o si mo laulau?
A we o nin' eje Od'agutan?
Aso re ha mo lati pade Jesu?
A fo mo nin' eje Od'agutan
Okan re ha mura fun 'le didan ni?
K'a we o nin' eje Od'agutan?
A we O n'nu eje
Ninu eje ti nwe okan mo?
Aso re ha funfun, o si mo laulau?
A we o nin' eje Od'agutan?
Bo ewu eri-ese si apakan,
K'a we o nin' eje Od'agutan?
Isun kan san fun gbogbo okan aimo,
Jo lo we nin' eje Od'agutan.
A we O n'nu eje
Ninu eje ti nwe okan mo?
Aso re ha funfun, o si mo laulau?
A we o nin' eje Od'agutan?