Loading...

Download
  • Genre:Afrobeats
  • Year of Release:2020

This song is not currently available in your region.

Lyrics

Kristi Yo Gba Elese - EmmaOMG

...

Igba aimọ yi, l'Ọlorun f'oju fo da

O si npaṣẹ fun eniyan n'ibi gbogbo lati ronupiwada

Oh my God!

Igba aimọ yi, l'Ọlorun f'oju fo da

O si npaṣẹ fun eniyan n'ibi gbogbo lati ronupiwada

Igba aimọ yi, l'Ọlorun f'oju fo da

O si npaṣẹ fun eniyan n'ibi gbogbo lati ronupiwada

Kristi o gba ẹlẹṣẹ

Kede rẹ fun gbogb'ẹda

Awọn ti wọn ṣako lọ

Awọn ti wọn ti ṣubu

Kọ l'orin, k'o si tun kọ

Kristi ngba awọn ẹlẹṣẹ

Fi ooto na ye wọn pe

Kristi ngba 'wọn ẹlẹṣẹ

'Toripe...Igba aimọ yi, l'Ọlọrun f'oju fo dá oo

O si npaṣẹ fun eniyan n'ibi gbogbo lati ronupiwada

Igba aimọ yi, l'Ọlọrun f'oju fo dá oo

O si npaṣẹ fun eniyan n'ibi gbogbo lati ronupiwada

Wa y'O fun ọ n'isimi

Gbagbọ Ọrọ Rẹ daju

Y'O gba t'o ẹniburu ju

Kristi ngba awọn ẹlẹṣẹ

Kọ l'orin, k'o si tun kọ

Kristi ngba awọn ẹlẹṣẹ

Fi ooto na ye wọn pe

Kristi ngba wọn ẹlẹṣẹ

Nitoripe...Igba aimọ yi, l'Ọlọrun f'oju fo dá ọ (Ó ti dáríjì wa)

O si npaṣẹ fun eniyan n'ibi gbogbo lati ronupiwada

Igba aimọ yi, l'Ọlọrun f'oju fo da

O si npaṣẹ fun eniyan n'ibi gbogbo lati ronupiwada


Ọkan mi damil'are

Mo mọ niwaju ofin

Ẹnit'o ti wẹ mi mọ

Ti san gbogbo gbese mi

Kọ l'orin, k'o si tun kọ

Kristi ngba awọn ẹlẹṣẹ

Fi ooto na ye wọn pe

Kristi ngba 'wọn ẹlẹṣẹ

Ani 'toripe...Igba aimọ yi, l'Ọlọrun f'oju fo da

O si npaṣẹ fun eniyan n'ibi gbogbo lati ronupiwada

Óò.. Igba aimọ yi, l'Ọlọrun f'oju fo da

O si npaṣẹ fun eniyan n'ibi gbogbo lati ronupiwada

Kristi ngba 'wọn ẹlẹṣẹ

A n'emi t'o ku f'ẹṣẹ

O ti sọ mi di mimọ

Mo ba wọn 'jọba Ọrun

Mo kọ l'orin, k'o si tun kọ

Kristi ngba awọn ẹlẹṣẹ

Fi ooto na ye 'wọn pe

Kristi ngba 'wọn ẹlẹṣẹ

Kọ l'orin, k'o si tun kọ

Kristi ngba awọn ẹlẹṣẹ

Fi ooto na ye wọn pe

Kristi ngba 'wọn ẹlẹṣẹ


Wa ẹlẹṣẹ pada s'ile

Jesu npe, ọ pe ko ma bo

O npe ọ pe pada wale

O npe ọ o...

Wa ẹlẹṣẹ pada s'ile

Jesu npe, ọ pe ko ma bo

O npe ọ pe pada wale

Baba npe ọ o...

Igba aimọ yi, l'Ọlọrun f'oju fo dá o

O si npaṣẹ (Come unto Him, all ye that labour) fun eniyan n'ibi gbogbo lati ronupiwada

Ọlọ́run fẹran aráyé t'obẹ gẹ, O f'Ọmọ bibi Rẹ kanṣoṣo fún wa, k'ẹnikẹni bá le gbà a gbọ́

Kò ronupiwada kúrò 'nù ẹṣẹ, lati ronupiwada

Igba aimọ yi, l'Ọlọrun f'oju fo dá o

O si npaṣẹ fun eniyan n'ibi gbogbo lati ronupiwada


Bíbélì wípé.. Kiyesi i, emi mbọ̀ kánkán; ère mi si mbẹ pẹlu mi, lati san an fun olukuluku gẹgẹ bi iṣẹ ọwọ rẹ̀

Behold, I come quickly; and my reward with me, to give every man according to his works (Revelation 22:12)

... gbogbo lati ronupiwada


Gba Jésù loni..


O my God!




....JESU YO GBA ẸLẸṢẸ... CHRIST RECEIVETH SINFUL MEN

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status