Loading...

Download
  • Genre:Afrobeats
  • Year of Release:2020

This song is not currently available in your region.

Try the alternative versions below.

Lyrics

Aigbagbo Bila - EmmaOMG

...

If no say na God dey help you, make you say Yes ooo.. Yes ooo

Oh my God!

Aigbagbọ, bila! t'emi l'Oluwa

Oun yo si dide fun igbala mi

Aigbagbọ, bila! t'emi l'Oluwa

Oun yo si dide fun igbala mi

Ki nṣa mã gbàdúrà, ki nṣa mã gbàdúrà, Oun yo ṣe 'ranwọ

'Gba Krist' wà l'ọdọ mi, ifoya kò si


B'ọna mi ba ṣú, Oun l'o ṣa ntọ mi

Ki nṣa gbọran ṣa, Oun yo si pèse

B'ọna mi ba ṣú, Oun l'o ṣa ntọ mi

Ki nṣa gbọran ṣa, Oun yo si pèse

Bi iranlọwọ ẹ, bi iranlọwọ ẹda gbogbo ṣáki

Ọrọ t'ẹnu rẹ sọ y'o b'ori dandan


Ifẹ t'o nfi hàn ko jẹ ki nrò pe

Y'o fi mi silẹ ninu wahala

Ifẹ t'o nfi hàn ko jẹ ki nrò pe

Y'o fi mi silẹ ninu wahala

Iranwọ ti mo sì, iranwọ ti mo si nri l'ojojumọ

O nkì mi layà pe emi o la já


Emi o ṣe kùn 'tori ipọnju

Tabi irora O ti sọ tẹlẹ

Emi o ṣe kùn 'tori ipọnju

Tabi irora O ti sọ tẹlẹ

Mo m'ọrọ Rẹ p'awọn, mo m'ọrọ Rẹ p'awọn ajogun 'gbala

Nwọn kò le ṣaikọja l'arin wahala.


Ẹda kò le sọ kikoro ago

T'Olugbala mu, k'ẹlẹṣẹ le yè

Ẹda kò le sọ kikoro ago

T'Olugbala mu, k'ẹlẹṣẹ le yè

Aye Rẹ tilẹ bù, aye Rẹ tilẹ buru ju t'emi lọ.

Jesu ha le jiya, k'emi si ma sa?


Njẹ b'ohun gbogbo ti nṣiṣẹ ire

Fun awọn t'o duro de Oluwa

Njẹ b'ohun gbogbo ti nṣiṣẹ ire

Fun awọn t'o duro de Oluwa

B'oni tí lẹ koro, b'oni tí lẹ koro ṣa ko ni pẹ mọ,

'Gbana orin 'ṣẹgun yio ti dùn to

Ki nṣa mã gbàdúrà, ki nṣa mã gbàdúrà, Oun yo ṣe 'ranwọ

'Gba Krist' wà l'ọdọ mi, ifoya kò si


Oya oya.... Aigbagbọ, bila! Aigbagbọ, bila!

T'emi l'Oluwa, T'emi l'Oluwa

Oun yo si dìde, Oun yo si dide

Fun igbala mi, fun igbala mi


Ki nṣa mã gbàdúrà, gbàdúrà s'Oluwa

Kí nṣa má gbàdúrà, s'Ọba Olúwa, Ọba on ibú-ọrẹ, Òun a dìde fún ìgbàlà mi o

Ki nṣa mã gbàdúrà, ki nṣa mã gbàdúrà, Oun yo ṣe 'ranwọ

'Gba Krist' wà l'ọdọ mi, ifoya kò si


Ki nṣa mã gbàdúrà, ki nṣa mã gb'adura Oun yo ṣe 'ranwọ

Oun yo ṣe 'ranwọ

'Gba Kristi wà l'ọdọ mi, ifoya kò si


Oh my God!



...AIGBAGBỌ BILA (BEGONE UNBELIEF)...

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status