Loading...

Download
  • Genre:Afrobeats
  • Year of Release:2020

This song is not currently available in your region.

Lyrics

Hallelujah Ayo Wa Mbo - EmmaOMG

...

Má sọ 'retí nù ọrẹ

O my God!

Gbogbo nkan d'ojuru, ó tí sú ọ

Ṣùgbọ́n má sọ 'retí nù ọrẹ, b'ó ti wù k'ó lè to

Mo ní ròhìn ayọ fún ọ ó, t'ẹti kò gbọ

B'ẹkun pẹ d'alẹ kan o, Ayọ mbọ l'owurọ

B'ẹkun pẹ d'alẹ kan o, Ayọ mbọ l'owurọ

Má sọ 'retí nù ọrẹ, Ayọ rẹ kò ní pẹ mọ

Owurọ rẹ tí de tán, Ayọ rẹ kò ní pẹ de

'Toripe... ALLELUYA! Ayọ wá mbọ, àwọn áńgẹ́lì t'ọrùn mbọ, l'ati mú bukun wá fún wa

K'ayọ wá lè bá wà d'opin

Àwa ti nw'oju Olúwa, k'a má ṣe jẹ k'arẹ mú wa

Gbogbo wa la o rí 'bukun gba, l'agbára Baba wa ọ̀run

Àní b'ẹkun pẹ d'alẹ kan o, Ayọ mbọ l'owurọ

B'ẹkun pẹ d'alẹ kan o, Ayọ mbọ l'owurọ

Má ṣe sọ 'retí nù ọrẹ, Ayọ rẹ kò ní pẹ mọ

Má sọ 'retí nù b'Olúwa ti mbẹ, Ayọ rẹ kò ní pẹ de

ALLELUYA! Ayọ wá de, àwọn áńgẹ́lì t'ọrùn de, wọ́n ti mú 'bukun wá fún wa

K'ayọ wá lè bá wà d'opin

Àwa ti nw'oju Olúwa, k'a má ṣe jẹ k'arẹ mú wa

Gbogbo wa la o rí 'bukun gba, l'agbára Baba wa ọ̀run


B'ẹkun pẹ d'alẹ kan o, Ayọ mbọ l'owurọ

Àní b'ẹkun pẹ d'alẹ kan o, Ayọ mbọ l'owurọ

Má ṣe sọ 'retí nù ọrẹ, Ayọ rẹ kò ní pẹ mọ

Má ṣe da 'retí nù, Ayọ rẹ kò ní pẹ de

Àní b'ẹkun pẹ d'alẹ kan o, Ayọ mbọ l'owurọ

Weeping may endure for a night but joy comes in the morning

Bí Jesu at'Ẹmi Rẹ ti mbẹ, Ayọ rẹ kò ní pẹ mọ

Olúwa yo 'nù omije re nu, Ayọ rẹ kò ní pẹ de

Àwa t'o nw'oju Olúwa, Àwa ti nw'oju Olúwa, k'a má ṣe jẹ k'arẹ mú wa

Gbogbo wa la o rí 'bukun gba, l'agbára Baba wa ọ̀run

O my God!



....ALLELUYA! AYO WA MBO... HALLELUJAH! OUR JOY COMETH...

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status