Iba Se P'oluwa Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2020
This song is not currently available in your region.
Lyrics
Iba Se P'oluwa - EmmaOMG
...
baba mi Mo you ma mi fun o o
Po Jo Oni soju mi(echo)
Bi ba nse poluwa ,to to wa ni to wa
loye ka wa ma wi
nigba te sun gbo gun dide.
ope ni foluwa ,oba olore
Ase ba kabiyesi re
afope fun Jehova to gba wa lowo ota
adupe oluwa.
Chorus:Baba mi Mo to ma mi fun o
Pojo Oni shoju mi...
Won ba bo wa mole
Pelu Agbara won
Ope ni foluwa
Ti ko je ki tesu bori
Ope ni foluwa
Baba olore
Aseba kabiyesi re
Afope fun Jehova to gba wa lowo ota
Adupe oluwa...
Baba mi... Mo yi ka mi fun o
Fun ojo Oni shoju mi
Okan wa yo Fe re
Nu oku wa pere
oku ja awa yo
eyo Jesu da wa sile
Ope ni fun oluwa.....
Afope fun Jehova to gba wa lowo ota
Adupe oluwa....
Baba mi Mo yi ka mi fun o
Fun ojo Oni shoju mi...echo