Loading...

Download
  • Genre:Afrobeats
  • Year of Release:2020

This song is not currently available in your region.

Lyrics

Oba Aiku Airi / Ore Bi Jesu (Medley) - EmmaOMG

...

Oba aiku, airi, orisun ogbon

To wa n'nu imole t'oju kole wo,

Olubukun julo, Ologo julo,

Alagbara, Olusegun, 'Wo la yin.

Laisimi, laiduro, ni idakeje,

O njoba LO, O ko si se alaini;

Giga ni idajo Re bi oke nla,

Ikuku Re b'isun ire at'ife.

O nte gbogbo eda alaye lorun

Nipa imisi Re won ngbe igbe won

A ndagba, a ngbile bi ewe igi

Asi nro; sugbon bakanna l'Olorun

Baba nla Ologo Imole pipe

Awon angeli Re wole l'ese Re!

Iyin wa la mu wa, jo ran wa l'owo

K'a le r'ogo imole to yi O ka

Ore bi Jesu kosi laye yi,

Oun nikan l'ore otito,

Ore aye yi y'o fi wa sile;

Sugbon Jesu ko je gbagbe wa.

Ah! ko je gbagbe wa;

Ah! ko je gbagbe wa;

Sugbon Jesu ko je gbagbe wa.

Akoko nkoja lo laifota pe;

A f'ojo kan sunmole wa si;

Onidajo mbo, gongo yi o so;

Awawi kan kosi l'ojo na.

Ah! ko je gbagbe wa;

Ah! ko je gbagbe wa;

Sugbon Jesu ko je gbagbe wa.

Duro d'Oluwa, ma siyemeji

Ohunkohun t'o wu ko le de;

'Gbat' o ro p'o pin 'ranwo Re y'o de;

Eni 'yanu l'Oba Oluwa.

Ah! ko je gbagbe wa;

Ah! ko je gbagbe wa;

Sugbon Jesu ko je gbagbe wa.

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status