Loading...

Download
  • Genre:Afrobeats
  • Year of Release:2020

This song is not currently available in your region.

Lyrics

Ogo Ni F'oluwa / Ija D'opin (Medley) - EmmaOMG

...

Oh my God!!


Ogo ni f'Oluwa t'O ṣe ohun nla

Ifẹ lọ mú k'O fún wa ní Ọmọ Rẹ

Ẹnit'O f'ẹmi Rẹ le lẹ f'ẹṣẹ wa

T'O sì ṣi 'lẹkun iye s'ilẹ fun wa


Yin Oluwa, yin Olúwa, F'iyin fun Olúwa

Yin Oluwa, yin Olúwa, ẹ yọ n'iwaju Rẹ

K'a tọ Baba wa lọ, l'orukọ Jesu

Jẹ k'a jọ f'ogo fún oníṣẹ 'yanu


Irapada kíkún ti Ẹjẹ Rẹ rà

F'ẹnikẹni t'o gba ileri Rẹ gbọ

Ẹni t'o buruju t'o ba le gbagbọ

L'ójú kanna yio ri idariji gba


Yin Oluwa, yin Olúwa, f'iyin fun Olúwa

Yin Oluwa, yin Olúwa, ẹ yọ n'iwaju Rẹ

K'a tọ Baba wa lọ, l'orukọ Jesu

Jẹ k'a jọ f'ogo fún oníṣẹ 'yanu


--


O ṣ'ohun ńlá fún wa, O da wa l'ọla

Ayọ wa di kikún ninu Ọmọ Rẹ,

Ògo ati ẹwa ìràpadà yi

Yo yà wá l'ẹnu 'gbati a ba ri Jesu

Ẹ yín Olúwa.. Yin Oluwa, yin Olúwa, F'iyin fun Olúwa

Yin Oluwa, yin Olúwa, ẹ yọ n'iwaju Rẹ

K'a tọ Baba wa lọ, l'orukọ Jesu

Jẹ k'a jọ f'ogo fún oníṣẹ 'yanu

Ẹ yín Olúwa.. Yin Oluwa, yin Olúwa, Orúkọ Rẹ ti n'ìyìn to

F'iyin fun Olúwa (ní gbogbo ayé, ẹ f'iyin F'Oluwa, t'O kú f'ẹṣẹ wa)

Yin Oluwa, yin Olúwa, ẹ yọ n'iwaju Rẹ

K'a tọ Baba wa lọ, l'orukọ Jesu

Jẹ k'a jọ f'ogo fún oníṣẹ 'yanu

'Toripe.. Ija d'opin, ogun si tan

Olugbala jagun molu

Orin ayọ l'a o ma kọ, Alleluya!

Gbogbo ipa n'iku ti lo;

Ṣugbọn Kristi f'ogun rẹ ka:

Aye! ẹ ho iho ayọ, Alleluya!

Ọjọ mẹta na ti kọja;

O jinde kuro ninu oku,

Ẹ f'ogo fun Oluwa wa, Alleluya!

O d'ẹwọn ọrun apadi,

O ṣilẹkun Ọrun silẹ

Ẹ kọrin iyin 'ṣẹgun Rẹ, Alleluya!

Jesu Kristi nipa iya t'O jẹ,

Gba wa lọwọ oro ikú

K'a le ye, k'a si ma yin Ọ, Alleluya


Yin Oluwa, yin Olúwa, F'iyin fun Olúwa

Yin Oluwa, yin Olúwa, ẹ yọ n'iwaju Rẹ

K'a tọ Baba wa lọ, l'orukọ Jesu

Jẹ k'a jọ f'ogo fún oníṣẹ 'yanu


Yin Oluwa, yin Olúwa, F'iyin fun Olúwa

Yin Oluwa, yin Olúwa, ẹ yọ n'iwaju Rẹ

K'a tọ Baba wa lọ, l'orukọ Jesu (Jésù l'ọna iye at'otitọ)

Jẹ k'a jọ f'ogo fún oníṣẹ 'yanu



Ẹ jẹ k'a jọ f'ogo fún oníṣẹ 'yanu oo

Jẹ k'a jọ f'ogo fún oníṣẹ 'yanu

Ifè aitegbẹ t'Ó ní sì wa lọ fi f'Ọmọ bibi Rẹ kan ṣoṣo, ṣe 'rúbọ f'ẹṣẹ wá ó..

Jẹ k'a jọ f'ogo fún oníṣẹ 'yanu


K'a ṣe é l'Ọba ó b'O tí tọ, Ọba àwọn ọba óò.. Ìràpadà kíkún má l'ẹjẹ Rẹ ra oo

Jẹ k'a jọ f'ogo fún oníṣẹ 'yanu


Ẹ yín Olúwa óò.. Yin Oluwa, yin Olúwa, f'iyin fun Olúwa

Yin Oluwa, yin Olúwa, ẹ yọ n'iwaju Rẹ

K'a tọ Baba wa lọ, l'orukọ Jesu

Jẹ k'a jọ f'ogo fún oníṣẹ 'yanu


Glory to God, Great things He has done

Praise the Lord for everything He's done

Glory to God, Great things He has done

Praise the Lord for everything He's done


Glory to God...

Oh my God!!


....OGO NÍ F'OLUWA/ÌJÀ D'ÒPIN (Medley) ...

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status