Loading...

Download
  • Genre:Juju
  • Year of Release:2000

Lyrics

Ogidan O Ni Se Barber - King Sunny Ade

...

koti wù kewure tóbi to

Ko da ko j'erin lọ

To ba f'oju d'koko

O ni lati parẹ

Ogidan o ni se barbar

K'aja de be lo gerun


Koti wu kewure tobi to

Ko da ko j'erin lo

To ba f'oju d'koko

O ni lati parẹ

ogidan oni se barbar

K'aja de be lo gerun


ogidan oni se barbar

K'aja de be lo gerun

Agere loni gbàdúrà

to ba dé òdò apare

ogidan oni se barbar

K'aja de be lo gerun


Agere loni gbàdúrà

to ba dé òdò apare

ogidan oni se barbar

K'aja de be lo gerun


taja ba wo àgbàdá iná

ki amọtẹkun ko wewu eje

ologini tẹ'n rí ni ko

ok so àkísà lasan ni ọ

gbogbo àpapọ

abere igi n'won se

ogidan oni se barbar

K'aja de be lo gerun


yiyọ ẹkun ni tojo ko

awa ọ kéré

suru lani

yiyọ ẹkun ni tojo ko

awa ọ kéré

awa ọ kéré

suru lani


ológbò to sun bi oke

òun tio ma jẹ lon'wa

awa ọ kéré

awa ọ kéré

suru lani


owo ajá ni o to

owo ajá ni o to

owo ajá ni o to

owo ajá ni o to

ìjímèrè tó ní òun o le re sa

owo ajá ni o to


t'aja ba ní òun ọ fe gbọ

ta basọ teleyin oni gba

t'aja ba ní òun ọ fe gbọ

ta basọ teleyin oni gba

àjọ peregun ka na

bẹ fẹ bẹ kọ

ojo lọkọ àgbàdo

ninu igbajo ará mi ni màrìwò

se sọ ọ ja rè


t'aja ba ní òun ọ fe gbọ

ta basọ teleyin oni gba

t'aja ba ní òun ọ fe gbọ

te basọ teleyin oni gba

àjọ peregun ka na

bẹ fẹ bẹ kọ

ojo lọkọ àgbàdo

ninu igbajo ará mi ni màrìwò

se sọ ọ ja rè


bẹ fẹ bẹ kọ

ojo lọkọ àgbàdo

ninu igbajo ará mi

ni màrìwò

se sọ ọ ja rè

Similar Songs

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status