I Shout Hallelujah! Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2020
This song is not currently available in your region.
Lyrics
I Shout Hallelujah! - EmmaOMG
...
Jesu tí f'ọna hàn mi
Kúrò n'nu òkùnkùn mi
'Tori na mo k'Alleluya ooo
('Tori na mo k'Alleluya o)
(Bọ sì bí k'ó jẹ k'a yọ)
(Bọ sì bí k'ó jẹ k'a yọ)
(Ẹ kira fún Baba, Ok)
Mo ní, O wẹ mi n'nu ẹṣẹ mi
O wo mi san n'nu àìsàn mi
'Tori na mo k'Alleluya ooo
('Tori na mo k'Alleluya o)
(Bọ sì bí k'ó jẹ k'a yọ)
(Bọ sì bí k'ó jẹ k'a yọ)
(Ẹ kira fún Baba)
'Torí na, mo yín Jésù Kristi
'Torí p'Oun ló tó bi
Fún ọrẹ t'Ó ṣe fún mi, b'o ṣe pọ bí ìṣàn omi
Jesu Baba àgbà, ọna iye t'o daju
Ẹjẹ Rẹ l'O fi gba mi là, eṣù ó lè pọn mi l'ójú mọ
Njẹ bawo ni má ṣe sọ, ọrẹ tí Baba ṣe fun mi
B'ẹnu mi jẹ ki kí ahọn, kò tó láti sọ ọ̀ tan
'Tori na mo k'Alleluya ooo
('Tori na mo k'Alleluya o)
(Bọ sì bí k'ó jẹ k'a yọ)
(Bọ sì bí k'ó jẹ k'a yọ)
(Ẹ kira fún Baba)
Àwọn ọrùn o, nsọrọ ogo
Àwọn ọ́run o, nwọ a yín in l'ogo
Ofurufu, wọn fi ìṣẹ ọwọ Rẹ hàn o
Èmi na, mo nyín Baba
'Tori na mo k'Alleluya ooo
('Tori na mo k'Alleluya o)
(Bọ sì bí k'ó jẹ k'a yọ)
('Tori na mo k'Alleluya o)
Àwọn òkúta, wọ́n ó ní yìn Ọlọ́run o
('Tori na mo k'Alleluya o)
Jehovah is so good to me
('Tori na mo k'Alleluya o)
Drum beats talk fades off...
Oh my God.....
End