Oju Oro Lyrics
- Genre:Traditional
- Year of Release:2020
Lyrics
Oju Oro - Ajogbajesu Twins
...
OJu oro lonleke omi
Oshi bata Lon like odo
Emi ni ma bori gbogbo ota mi pata
Ota ile ota ode o/4ce
Ejire, omo ajogbajesu
Iwo lOlorun to dabira
Dakun magba fawon elegan
Ton ba mi gbogun Awon ni won mo
Koto yewon baba je o pe
Kan to damo baba je o pe
Aye nle mi m, kan ma mumi
Araye o fe nkan to da /2ce
Iwo lolorun alagbara
Dakun wa se tawa ko da
Kaye awa malo lofo
Koju emi mase pon wa
Koju ara mase pon wa
Larin ota ati elegan
Jare wase tawa nire /2ce
OJu oro Lon leke omi
Osi bata lon leke odo
Emini ma bori gbogbo ota mi pata
Ota Ile ota ode o
***************