Loading...

Download
  • Genre:Gospel
  • Year of Release:2020

This song is not currently available in your region.

Lyrics

Arojinle (Deep Thought) - Adeyinka Alaseyori

...

Mo regbe mi ton shala lakitan

Mo regbe mi tin won dawopo fun jeun lorita

Mo regbe mi taye ti ya no were o

Emi o seni yin o baba

Aika Moye egbe mi, tin won o le da seun kohun fun rawon

Emi to fun loju, fun lowo fun ni gbogbo eya ara, gbogbo re Sa ni mo wa dupe fun

Omo o ku momi lowo Oko o momi Lori mowa lalafia o

Emi o seni yin o baba

Mo ro arojinle Lori aye mi o

Ibi anu bayemi de o Arojinle no mo ro

Mo roooooo arotunro o

Lati igba ti o si nkankan to fi gbemi de bi mo de

Igba taye sope otitan ti wo olorun so ni gbangban pe oku

Awon ileku taye sope awon ti ti

Ti wo olurun sope osi

Emi ro arotunwo mo ro arojinle oo

Ibi anu bayemi de o

Arojinle ni mo ro

Gbogbo igba tin mo n wo moto mo n bole layo

Kin se gbogbo eniyan to n wo moto lodele won pada o

Awa tan n Jade nile ta n bale lalafia eje a dupe

Awa tolorun o gba kibi o kogun sile ejaka gbega

Ai moye egbe wa to n be ni mortuary

Aika moye egbe wa ti won ti rale fun ni graveyard o

Iwo tolorun dasi to n yo ninu ewu lojojumo o je gbega o

Aanu ni morigba o o aanu sa lo ri o o ooo

Moro arojinle lori aye mi o

Ibi aanu baye mi de o, arojinle ni mo ro

Igba kan ri mo pelu awon to n toro aso wo

Igba kan ri a pelu awon ti ko le da jeun funrawa

Igba kan apelu awon to n bebe koto dipe adahun rere se o

Ewo bi aanu ran wa lowo de o

Ewo bi aanu mu wa lowo dani de mu wa rinrin ogo to jagu

Eja a dupe lowo olorun oba

Oke talagbara gun to n mi ele

Oke talagbara gun to n mi ele

Ohun lemi omore gun ti mofayo wa dupe

Oke ti alagbara gun to n mi ele

Odun to koja talagbara lo taye gbomo pa lowo won eh

Oro talagbara so ti won o fi laju saye mo o

Aso talagbara kan wo ti won jo eni tan wa lati pa

Ohun talagbara se todipe won won bewo wo lositu deni eleni oje dupe

Iwo to lafani lati ma se bo se wu e ninu olala olorun oje dupe

Iwo to n jeun lasiko to n momi lasiko o je dupe daada lowo olorun

Aika moye awon eniyan ti won fegba fun lounje je kakiri

Eh aika moye awon eniyan to n fegba sope kan losun to n sope kan lo ji

Oke ti alagbara gun to n mi ele

Emi wo mo wo, emi wo mo wo

Emi wo o, mo wo yika

Mori pope ye baba

Ose fun aanu to ga ti mo ri

Ose fun iranlowo ti o legbe ti o fi bami rinrin ajo yi o

Iba je eyan lo n da bobo bo gbogbo wa ni a o ba ti sesin

Iba je eyan lo n bo asiri wa won o ba ti ja wa si wowo ni gbangba

Olorun ti o gba kaye tu aso lara wa lojiji e ja jo ki o

Olorun ti o gba kaye gbomo pa lowo wa e ja sowipe o se o

Olorun ton mu wa dubule lalafia to mu wa soji lalafia o

Ipa wa ko agbarawa ko

Olorun lo n gbe aye duro

Base n lo, base nbo irorun loba de

Iwo to kuro nile to ba ile lalafia o je dupe dada lowo olorun

Aika moye eniyan to dagbere nile to je pe nigba to n ma pada dele Ile ti darowo

Ati omo ati oko ati aya ati oun ini won gbogbo re lo jo mole

Iwo ti olorun da si ni level by levels o je dupe lowo olorun o

Alabo nibi ti ko si abo

Oluranlowo wa lojo ogun le

Ipa! to te aye wa siwaju ni gba toye kayewa ma lole Asiri wa to bo Iwo ni

Agbara to n fun wa ni idahun ebe adura wa ni Koko oun so di testimony ni gbangba iwo lope ye

Emi Inu awon woli okan awon ajiyin rere o

Ogo ogo ogo ogo ogo ni foruko re o

Ai moye awon oloju meji to n soda titi to moto n pa

Iwo to loju meji to n soda layo olorun lo mu wa lowo dani soda

Kin se ipa wa kin se agbara wa

Abo olorun lo daju lori wa o

Eje Jo ki o, eja Jo gbega

Oni duro mi e seun o

Agbejoro mi ema seun o

Bo jeniyan lo n duro ni wa ti ma soro

Bo jeniyan lo n duro ni wa ti salo

Bo jeniyan lo n duro ni wa ti ma siregun

Oni duro me e seun o

Kin se mimo se

Kin se agbara mi

kin se titobi mi o, le se dami si o baba

Asiri to n gba yiti ninu osumare a gbe o ga

Eni kerin ninu Ina ileru

Ogo to wonu ofo eniyan to n mogo Jade o

Ogo to kale sinu eniti o je ofo , to je korofo to mu ogo ja gbangba

Owo!

owo eniti o se agbara to n sise iyanu nla o

Ohun enit' oun fa igi gbe to n fagi kedari ya

Ina saju re losi ogun ojo gbogbo awon ota re run o

Iwo to pase pe ki Ina Jo, lori igbe ti igbe ko si run

Iwo to pase kina ma Jo lori igbe ti igbe kosi run o

Owo nla ipa nla

Algbara nla

Oloruko aperire

Ina loju ina lenu

Eni kerin ninu Ina ileru o

Ayeraye ninu eni ti aye toro aye lati ma je ayeraye

Orogun gbo gun je, orogun gbogun mi

Orogun na'gun legba o

Kiniun nla to n fa kiniun aye gbogbo le nu ya

Oba to pase awe fawon kiniun ninu Iwo kiniun loje yen o

Leyin awe olojo meta to pase fawon kiniun

Obo won pelu awon ota danieli tile tile won

Olorun nla oloruko nla oloruko apekore oloruko aperire

Akoda aseda ameda

Gbani gbani ti aye saya

Ope lamuwa iyin lamuwa

Ounje yin la gbe wa kin se nipa iwa mimo

Kin se nipa iwa mimo, Kin se nipa iwa mimo

Mo wa dupe ore atodun mo dun

Mowa dupe ore atosomo su o

Mo wa dupe ore igba gbogbo

Emi na re oluwa

Irin ajo oju ala awon omo wa Iwo lo o gba kiwon toju orun de oju iku

Ala lile t'awon omo wa la

Iwo ni o gba kaye pa won loju orun

Awa ta n ji saye lojojumo, kin se agbara wa kin se ipa wa

Kin se gbogbo eniyan to sun lale lo n ji

Awa tolorun ji saye e ja sope o se

Aika moye awon te Jo wo labor room lojo to bimo to











Similar Songs

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status