Èyan JÉSÙ ft. Monique & A'dam & Bidemi Olaoba Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2020
Lyrics
Èyan JÉSÙ ft. Monique & A'dam & Bidemi Olaoba - Mike Abdul
...
Intro
Wos
Eyan Jesu
Jesu lo ni Central Bank (eh.. Central Bank)
Sister ṣẹṣẹde (ah.. Sister ṣẹṣẹde)
Ma people Ma people (People)
Oluwa lọ ni people
Ṣe you want to bring the street to church
No, we want to turn the street to church, Ok
Ma people Ma people
The people I get who will gather together forever
For better labari la sweeter orisa zativa
Tomero porero ororo
Oya dance eyan Jesu (eyan Jesu)
Oruko ẹ lọ kọ s'ori blessing (eyan Jesu)
Anu lọ ri gba eyan Messi (eyan Jesu)
World best ọmọ ologo champion (eyan Jesu)
cceeyan lo se bintin (eyan Jesu)
Oritsejafor o jẹ ki n l'ẹnu (eyan Jesu)
Oya put your name eyan Jesu (eyan Jesu)
Hashtag eyan Jesu
Oya fun wọn Lamba (Lamba)
Lamb of God (Lamba)
Tọ ba ṣe DNA test
Fun awọn eyan Jesu l'oṣuyi, ṣ'o ma wa (ṣ'o ma wa)
Sa 'rẹ wa gba Number (Lamba)
Special Number (Lamba)
Anyway you must to know what made the word
Oluwa si ni Ọrọ na
Oya gbe gbe ti (gbe gbe ti)
Padi ẹ f'ẹhin ti (gbe gbe ti)
Follow the Ladder (gbe gbe ti)
Wọn fẹ koronate ẹ (gbe gbe ti)
(Ayiii..) Ṣo ro (koro) koro (koro) No ro (koro)
Koro, l'obanikoro (koro) wọn ma ji soro, Koro
Oya dance eyan Jesu (eyan Jesu)
Orukọ ẹ lọ kọ s'ori blessing (eyan Jesu)
Anu lọ ri gba eyan Messi (eyan Jesu)
World best ọmọ ologo champion (eyan Jesu)
cceeyan lo ṣe bintin (eyan Jesu)
Oritsejafor o jẹ ki n l'ẹnu (eyan Jesu)
Oya put your name eyan Jesu (eyan Jesu)
Hashtag eyan Jesu
Eleyi tun wa contagious (suya contagious)
Ota l'ẹnu tẹtẹtẹ
T'ẹ ba ngbọ praise party (praise party)
Ọlọrun Ọba l'O ma play (Ọlọrun Ọba l'O ma play)
Kiri gbogbogbo (gbogbogbo)
Kiri gbagbagba (gbagbagba)
Do your hand like this (do your hand like this)
Sebi you wan receive (do your hand like this)
Ṣ'o d'owo mọ (ṣ'o d'owo mọ)
Ṣ'o fẹ sọ pe o mọ Jesu (ṣ'o fẹ sọ pe o mọ Jesu)
You want to know, You want to know, eh..
You gat to know, You gat to know eh..
You gat to know your God Jehovah eh..
go go go ti go ti go wos, go go go ti go ti go take it
Oya dance eyan Jesu (eyan Jesu)
Orukọ ẹ lọ kọ s'ori blessing (eyan Jesu)
Anu lọ ri gba eyan Messi (eyan Jesu)
World best ọmọ ologo champion (eyan Jesu)
cceeyan lo ṣe bintin (eyan Jesu)
Oritsejafor o jẹ ki n l'ẹnu (eyan Jesu)
Oya put your name eyan Jesu (eyan Jesu)
Hashtag eyan Jesu
Two thousand years lati bẹẹ̀rẹ̀ (bẹ̀ẹrẹ̀)
Unstoppable bí ti Pelé (Pelé)
Enemies wọn sa wọn nmi ẹlẹ (ẹlẹ)
Wọn get ẹ, ẹhn ki lo ń ṣẹlẹ̀
Call us the sauce, call us the fire
Ore-ọ̀fẹ́ yẹn no dey tire
We no Retreat, we no Surrender
Na we dey sell, na who be buyer
A n seek when ni Mount Zion
Ṣe communion pẹlu lion
O dabi Film mount Zion
Jesu mi re ati triumph
Oya f'ede fọ (Robo seke)
Lai wo we (Robo seke)
Mo s'ede ti o yẹ mi si nkan ti o yẹ mi, s'oluwa t'O ni gbgbo oye
Oya dance eyan Jesu (eyan Jesu)
Orukọ ẹ lọ kọ s'ori blessing (eyan Jesu)
Anu lọ ri gba eyan Messi (eyan Jesu)
World best ọmọ ologo champion (eyan Jesu)
cceeyan lo ṣe bintin (eyan Jesu)
Oritsejafor o jẹ ki n l'ẹnu (eyan Jesu)
Oya put your name eyan Jesu (eyan Jesu)
Hashtag eyan Jesu
End