Loading...

Download
  • Genre:Gospel
  • Year of Release:2020

Lyrics

Baba Ese - Christianah Orindoyin

...


Ose ose o ,fanu re lori mi

ifere dami si o mama se oba iye .

Chorus: Ose ose o ,fanu re lori mi

ifere dami si o mama se oba iye


Verse 1 : Mo n lo mo nbo layo arun o se mi sebi mi

anu re lo se yi fun mi o mama se oba iye.

Chorus: Ose ose o ,fanu re lori mi

ifere dami si o mama se oba iye


Verse 2: Eemi leni taye ti gbagbe iwo lo tun wa miri o,

tawa lemi o ba tun yin bi o se wo o oba.


Chorus: Ose ose o ,fanu re lori mi

ifere dami si o mama se oba iye


Verse 3: Egan gbogbo taye fi n pemi to gan oruko re ninu aye mi,

aanu re loyo mi puro ,

won pada dogo o ,

moyege )3x

titi aye.

Chorus: Ose ose o ,fanu re lori mi

ifere dami si o mama se oba iye

2x........

Lead :Ese ee baba moyin o logo oo

Response: Ese ee Baba ese gan.

Lead : Baba ema se oo

oloore .

Response: Ese ee Baba ese gan

Lead: Olorun to laye mi,

olorun toni gbami eseun.

Response: Ese ee Baba ese gan.

Lead: Arugbo Ojo ema se ,

baba moyin o logo.

Response: Ese ee Baba ese gan.

Lead: Bi gbogbo irun orimi je ahon ,

koto fun yin re o baba.

Response: Ese ee Baba ese gan.

Lead: Aiku aisa aidi baje ,

iyin re mare o

Response: Ese ee Baba ese gan.

Lead: Baba momu yin wa ese .

Response: Ese ee Baba ese gan.

Lead: Osuba re ni n omase ,

Olorun baba agba .

Response: Ese ee Baba ese gan.

Lead:-Nba tiku ota iba yomi ,

won lalakori omo ti lo.

Response: Ese ee Baba ese gan .

Lead. Sugbon ero ota imo ota yen ,

iwo lo sowon dasan ooo.

Response: Ese ee Baba ese gan

Lead: Baba ema oo ,

Oba to fimi reya mi lekun .


Response: Ese ee Baba ese gan.

Lead: Mokan sara si o ,

emi awon Woli iiii .

Response : Ese eee Baba ese gan .

Lead : Oba ni rin kiya o pari ,

olorun ara to lara.

Response : Ese eee Baba ese gan .

Lead : Baba momu yin wa ese ...

Response : Ese eee Baba ese gan .

Lead : Iwo loku gba mi o ,

lowo ogun ilemi .

Response : Ese eee Baba ese gan .

Lead : Mole rin mole sako

mole demo moti ni o .

Response : Ese eee Baba ese gan .

Lead : Mole rin mole sako ,

ewo mi bimo se nyan.

Response : Ese eee Baba ese gan .

Lead : Ese eee ,Ema se gan oooo.

Response : Ese eee Baba ese gan .

Lead : Titilai )3x

n o yin o o baba gba .

Response : Ese eee Baba ese gan .

Lead : Okuta ti won kosi le lojo si ,

Opada odigun ile.

Response : Ese eee Baba ese gan .

Lead : Orindoyin nyin o o ,

Olorun tewo gbope.

Response : Ese eee Baba ese gan .

Lead : Baba ema se o ,oloore .

Response : Ese eee Baba ese gan .

Lead : Molerin mole sako ,

mole demo moti ni o.

Response : Ese eee Baba ese gan .

Lead : Baba ema se o ,Oloore .

Response : Ese eee Baba ese gan .

Lead :- Baba momu yin wa, ese ...

Response : Ese eee Baba ese gan .......

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status