O Ni Gbogbo Aye (He's Got the Whole World) Lyrics
- Genre:World Music/Folklore
- Year of Release:2020
This song is not currently available in your region.
Lyrics
O Ni Gbogbo Aye (He's Got the Whole World) - EmmaOMG
...
Oya ẹ la ẹnu pe Jesu - JESU
O fi 'mọ́lẹ̀ bora bí aṣọ (Oh My God)
Wetin then dey cause fear gbà mo ti mọ Jesu
(Gba mo ti mọ Jesu o)
Why me I go dey dey fear nígbà mo ti gba Jesu
(Gba mo ti gba Jesu o)
Why me I go dey dey fear gbà mo ti mọ Jesu
(Gba mo ti mọ Jesu o)
Wetin then dey cause fear gbà mo ti gba Jesu
(Gba mo ti gba Jesu o)
Nitori O ní gbógbo ayé ni 'kawọ Rẹ
O ní gbógbo ayé (Jesu) ni 'kawọ Rẹ
O ní gbógbo ayé ni 'kawọ Rẹ
O ní gbógbo aye ni 'kawọ Rẹ
Jésù..
He's got the whole world in His hands
He's got the whole wide world in His hands
He's got the whole world in His hands
He's got the whole world in His hands
(Ọba t'O fi mímọ bora t'O f'aye ṣ'apoti itisẹ Rẹ, Edumare...)
Oh my God...