Talo Npe Mi Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:1997
Lyrics
Talo Npe Mi - Kingsley Ogunde
...
omo Mi
omo mi
ayanfe omo mi
talonpe Mi o
talonpe Mi o
talonpe Mi o
enikan bami soro lokan Mi
enikan bami soro ninu Mi
enikan un kan ilekun okan Mi
mio si mo eni to unje
un si mo eni to be
kini mo se oo
oni emini kinma seberu
o un pemi
oun pemi
enikan bami soro lokan Mi
enikan bami soro ninu Mi
ati ko nipa temi pe ma sorire 2x
at I KO nipa temi ibi onidebami o 2x
asiti KO nipa temi pun
emini ma siwaju won ninu olorire
ipe todara loluwa pemi oo
emi ni ma siwaju won ninu ololorire
ire mi aju tie lo
Ayo Mi aju tie lo