O Pari (It Is Finish) Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2017
Lyrics
O Pari (It Is Finish) - Tosin James Trinity
...
VERSE 1:
Bi eje ewure
ba n so alaimo di mimo
ati eje eyele
fun iwenumo tara )2ce
Melo melo nii
eje Jesu lo n we eriokan yin mo
kuro ninu oko ese lati sin Olorun )2ce
CHORUS:
(Opari o)
Opari) 3ce
Opari ni Jesu so ko to dake
Asepe) 3ce
Asepe in Jesu se ni Calvary
Opari) 3ce
Opari ni Jesu so ko to dake
Asepe)3ce
Asepe ni Jesu se ni Calvary
VERSE 2:
Nitori eyii
lo se je e
Alarina majemu titun
Awa ta o je eyan nigba kan ri
Eje re so wa d' omo
Nigba naa la wipe
o GBE iku mi ni isegun
Iku oro re da
Isa oku
Isegun re daa
(CHORUS) 2ce
iya pari
Jesu gbamila
irugbin esu
irugbin aisan
A fa tu ti gbon gbon ti gbon gbon
Laye mi o
O pari
Aisan pari o
Ese pari o
irobinuje pari
Lori okan mi o
ati ramipada
A so mi d' omo
A so mi d' alaye okan
nipase Eje Re
O parii
Ohhh oh pari laye mi
Osi pari
aisan pari
ijiya pari
irobinuje pari
mo d' alagbara
mo d' omo
mo d' omo ninu EJE RE
tori pe
ATIRAMIPADA