Abiamo Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2016
Lyrics
He sent His words to me and my soul
He gave me freedom of life inu mi dun
Laye o
He forged my life **
Mo nri owo Re lara eye oju orun
That’s why I call You Baba God
Iwo nikan nimo sesi o o
Abe Re nimo sawa
Mo kuna ogo Re o
Lai moye igba
On dari afefe lo o
Won kangi oko lara
Osupa mura lati ran o
Ise owo Re ni
Okunkun su lo o
Asele atun mo
Okunkun su lo o
Ojo ngori ojo
Kabiyesi se Wo nikan l’Oba Oloola
Iwo naa loju gbogbo Oba lo Oba lo
Kabiyesi se Wo nikan l’Oba Oloola o
Se Iwo naa loju awon Oba lo Oba lo
Abiamo o nigba ojo
Abiamo erun o
Abiamo o nigba iponju mi
Iwo l’Oluwa mi o
Abiamo o nigba ojo
Abiamo erun o
Abiamo o nigba iponju mi
Iwo l’Oluwa mi o
Mo kiyesi mo wole
Mo gbadura
Mo fori bale
I will lift Your name (I will lift Your name higher and higher) 3x
Nibo ni ko s‘Oluwa mi o
Awon kan won kuna ogo Re
Nibo ni ko s‘Oluwa mi o
Oro Re o laju afoju
Ebami soro (Baba mbe)
Okunkun su lo o
Asele atun mo
Okunkun su lo o
Ojo ngori ojo
Kabiyesi se Wo nikan l’Oba Oloola
Iwo naa loju gbogbo Oba lo Oba lo
Kabiyesi se Wo nikan l’Oba Oloola o
Se Iwo naa loju gbogbo Oba lo Oba lo
Abiamo o nigba ojo
Abiamo erun o
Abiamo o nigba iponju mi
Iwo l’Oluwa mi o
Abiamo o nigba ojo
Abiamo erun o
Abiamo o nigba iponju mi
Iwo l’Oluwa mi o
Ah ah ah ah Abiamo orun o
Eh eh eh eh Abiamo orun o
Oh oh oh oh Abiamo orun o
Eh ah eh ah Kabiyesi
Sewo nikan l’Oba olola o
Sewo naa loju gbogbo Oba lo
Kabiyesi Iwo nikan l’Oba olola
Iwo naa loju gbogbo Oba lo