Loading...

Download
  • Genre:Gospel
  • Year of Release:2018

Lyrics

Jesu Oba - Tosin Koyi

...

Key - (Response) & [Translation]

..................

Ará ẹ wá gbọ [Everyone, listen up]

Ìròyìn rere ni mo múwá. [I have brought the good news]

Ará ẹ wá gbọ [Everyone, listen up]

Ìròyìn rere [Good news] .


Everybody say Yeah, Yeah (Yeah, Yeah)

Yeah, Yeah (Yeah, Yeah)

Say Yeah (Yeah)

Yeah (Yeah)

Yeah Uh...


Ibanuje d' òpin [Sorrow is abolished]

(L'aiye wa [In our lives])

Ikú d' òpin [Death is abolished]

(L'aiye wá [In our lives]) .

Ẹ'ṣẹ' d' òpin [Sin is abolished]

(L'aiye wá [In our lives]) .

Àìsàn d' òpin. [Sickness is abolished]

(L'aiye wá [In our lives]).


Nitori, Ẹni tí a' reti ti dé [Because, the expected One has arrived]

(Ó dé, Ó dé [He is here, He is here])

Olùgbàlà aráyé de [The Saviour of the World is here]

(Ó dé, Ó dé [He is here, He is here])


Ẹni tí a' reti ti dé [The expected One has arrived]

(Ó dé, Ó dé . [He is here, He is here])

Olùgbàlà aráyé de [The Saviour of the world]

(Ó dé, Ó dé) [He is here, He is here]


Jésù Ọba! [Jesus the King]

(Ọba, Ọba awọn ọba) . [The King, King of all kings]

Jésù Ọba eh eh [Jesus the King]

(Ọba, Ọba awọn ọba) . [The King, King of all kings]

Je-Je-Jésù Ọba Oh oh! [Jesus the King]

(Ọba, Ọba awọn ọba) . [The King, King of all kings]

Eh eh Jésù Ọba oh oh! [Jesus the King]

(Ọba, Ọba awọn ọba) [The King, King of all kings]

..... Instrumentals.......


Imagine a virgin giving birth to a child

Imagine the Son of God here on Earth


For Bethlehem | (Beth-le-he-mu)

Mary born pickin o | (Born pickin o)

Three wise men dem | (Three wise men dem)

Dem dey find the King o | (Dem dey find the King)


Ẹni tí a' reti ti dé (Ó dé, Ó dé)

Olùgbàlà aráyé de!

(Ó dé, Ó dé)


Jésù Ọba eh! (Ọba, Ọba awọn ọba)

Je-Je-Jésù Ọba eh!

(Ọba, Ọba awoh oba)

Jésù Ọba! Jésù Ọba! Jésù Ọba!

(Ọba, Ọba Ọba àwọn oba)


Emmanuel Emmanuel eh-eh

Ọba, Ọba


The Son of God yeah

(Ọba, Ọba)


Ọba, Ọba (Ó dé)


Ọba eh (yeah yeah)

(Ọba Ọba Ọba Ọba)

(Ó dé) (Ó dé) (Ó dé) (Ó dé)

(Ọba, Ọba Ah) Ó de Ó de


Ọba eh

(Ọba ọba ọba ọba)

(Ó dé) (Ó dé) (Ó dé)

(Ọba, Ọba Ah) Ó de


Yeah, Yeah (Yeah, Yeah)

Yeah, (Yeah)

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status