Loading...

Download
  • Genre:Gospel
  • Year of Release:2016

Lyrics

[ti:02 Oba ni baba]


Igba mo fe jo re

Ni jesu gbe lu fun mi

Ma jijo jesu laye

Pelu idunnu okan

Eyin omo jesu ewipe

Oba ni baba


Alewilese oba to to aye

Oba ni baba

Aleselewi oba tin ba ni se

Oba ni baba

Ariro ala oba olori aye

Oba ni baba

Alanpanla to so ile aye mi ro

Oba ni baba

Erujeje jeje ninu awon orun o

Oba ni baba

Adabatubu awuwo mase gbe

Oba ni baba

Ako matika leyin

Arugbo ojo

Oba ni baba

Oba to doju ti koroba

To fi apere ponmi

Oba ni baba

Ogbingba tin gba alayilara

Jowo wa gba mi o

Oba ni baba


Erujeje l’oba o

Erujeje l’oba

Oba mimo l’oba tin mon sin

Erujeje l’oba

Erujeje l’oba

Oba mimo l’oba ti mon sin

Erujeje l’oba

Olugbala l’oba

Olugbala l’oba

Jehovah sikenu l’oba ti mon sin

Olugbala l’oba

Olugbala l’oba

Oba mimo l’oba ti mon sin

Olugbala l’oba

Oluwosan l’oba

Oluwosan l’oba

Jehovah rafah l’oba ti mon si

Oluwosan l’oba

Oluwosan l’oba

Oba mimo l’oba ti mon sin

Oluwosan l’oba

Abanti banti

Abanti banti

Adaba tubu l’oba ti mon sin

Abanti banti

Abanti banti

Oba mimo l’oba ti mon sin

Abanti banti

Abanti banti

Abanti banti

Adaba tubu l’oba ti mon sin

Abanti banti

Abanti banti

Oba mimo l’oba ti mon sin

Abanti banti

Abanti banti

Ajogando jogando

Afenfe fenfe

Oba mimo l’oba ti mon sin

Abanti banti

Abanti banti

Oba mimo l’oba ti mon sin

Abanti banti

Oluwosan l’oba

Oluwosan l’oba

Oba mimo l’oba ti mon sin

Oluwosan l’oba

Oluwosan l’oba

Oba mimo l’oba ti mon sin

Oluwosan l’oba


Ilesanmi o

Omo jesu ni won je

Baba taku o

Omo jesu ni won je

Ilesanmi o

Omo jesu ni won je

Baba taku o

Omo jesu ni won je

Babalola omo jesu ni won je

Ni 1930 o laye

Adeboye omo jesu ni won je

Awa redeem omo jesu lawa

Oyedepo omo jesu ni won je

Awa winners omo jesu lawa

Baba kumuyi omo jesu

Ni won je

Awa deeper omo jesu lawa

Adeyemi omo jesu ni won je

Awa day star omo jesu lawa

Oluwalano omo jesu ni won je

Baba ori oke sokun je

Ke pe

Ajishafe o omo jesu ni won je

Communal chapel sha le wa

Ke pe

Samuel omo jesu ni mi

Bari jesus

Mo jesu lawa


Ewa fun wa niyin

Iyin rere

Ewa fun wa niyin

Iyin rere

Ewa fun wa niyin

Iyin rere

Ewa fun wa niyin

Iyin rere

Ewa fun wa niyin

Iyin rere

Ewa fun wa niyin

Iyin rere


Ewa fun wa niyin

Iyin rere

Ewa fun wa niyin

Iyin rere

Ileasanmi o

Wa fun wa niyin

Iyin rere

Ewa fun wa niyin

Iyin rere

Abiara wa fun wa niyin

Iyin rere

Ewa fun wa niyin

Iyin rere

Baba kumuyi

Wa fun wa niyin

Iyin rere

Ewa fun wa niyin

Iyin rere


Ewa fun wa niyin

Iyin rere

Ewa fun wa niyin

Iyin rere

Oyedepo wa fun wa niyin

Iyin rere

Ewa fun wa niyin

Iyin rere

Samuli wa fun wa niyin

Iyin rere

Ewa fun wa niyin

Iyin rere

Bari jesu wa fun wa niyin

Iyin rere

Ewa fun wa niyin

Iyin rere

Ewa fun wa niyin

Iyin rere

Ewa fun wa niyin

Iyin rere

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status